THE ODDS WILL TURN IN YOUR FAVOUR
THE SEED
Is there anything too hard for God?” Jeremiah 32:27
No matter what you are passing through, I want you to believe and trust God that you will surely overcome. If nothing is too hard for God and He has promised us all our needs in life here and hereafter (including victory over challenges), then fear not. There is no excuse for fear of lack of supply, God will connect you to new helpers that will lift you up and make you a greater helper to others, believe for the best. You will surely laugh and laugh because you believe in a God that never fails and He is incomparable, with Him, all things are possible.
BIBLE READING: Isaiah 40: 26-31
PRAYER: Lord, I pray that all the odds that are preventing my rapid growth will turn in my Favour in Jesus name.
AWON AIDOGBA YIO SISE FUN RERE RE
IRUGBIN NAA
“Ohun kan ha wa ti o soro fun mi bi?” Jeremiah 32:27
Ko nifise iru ohun ti o n la koja, mo fe ki o gbagbo, ki o si gbekele Olorun wipe iwo yio bori dandan. Niwon bi ohunkohun ko ti soro fun Olorun, ti o si ti se ileri ohun gbogbo ti a nilo laye yi ati lorun fun wa (ati isegun lori gbogbo idojuko wa), ma beru mo. Ko si awawi fun iberu wipe o le se alaini. Olorun yio dari oloore miran ti yio gbe o soke ti yio si so o di oluranlowo nla fun awon elomiran. Gbagbo . o daju wipe iwo yio rerin, rerin nitoriti o gbagbo ninu Olorun ti kii se aseti, ti ko si ni afiwe. Ninu re, ohun gbogbo ni sise.
BIBELI KIKA: Isaiah 40:26-31
ADURA: Oluwa, mo gbadura wipe gbogbo aidogba ti n dena idagbasoke mi, yio sise fun rere mi ni Oruko Jesu. Amin