The Parable Of The Sower IV

THE SEED
“…But other seed fell on good ground and yielded a crop that sprang up, increased and produced: some thirtyfold, some sixty, and some a hundred.…” Mk. 4: 8 NKJV

The positivity and fruitfulness of the word of God in our lives depend on us the hearers. Therefore, be careful how you receive the Word of God; the more attention and focus you give to it, aids more blessings and fruit it will yield in your life. That is why when the blessing of God goes out in church, some people get 30%. While in the same place some people get 60%. And still, yet a few people get 100% of what God intends. This means that you will receive what you bid for. Our undivided attention to the words of God shows our commitment to accept what is been said to us and our positive response to the word we accept means that we are open to the Holy Spirit to work in us and make us productive by weeding out everything that is not of God in our life and planting every good seed that will make us the favour of the Father.

PRAYER
Heavenly Father I want to receive 100% of what You are giving us. Help me to pay the right attention to Your Word, in Jesus’ name Amen.
BIBLE READINGS:  1 Timothy 4:12-16

ÒWE AFUNRUGBIN lV

IRUGBIN NAA
“…ùgbon irúgbìn mìíràn bo sórí ilẹ̀ dáradára, won sì so èso kan tí ó hù, tí ó pọ̀ sí i, tí ó sì mú jáde: òmíràn ọgbọ̀n, omiran ọgota, omiran ọgorùn-ún…” Maaki. 4:8 KJV

Iwa rere ati eso ti ọrọ Ọlọrun ninu igbesi aye wa gbarale awa ti a je olugbọ. Nitorina, ṣọra bi o ṣe gba Ọrọ Ọlọrun bi o ti n farabale, ti o si n Fi okan sii, ni ibukun àti eso ti yio ma mu jade yio posi nínú aye re. Nigbatí ìbùkún Ọlorun bá jáde nínú ìjọ, àwọn kan yio gba Ida ogbon(30%), awon Kan yio gba Ida ọgota( 60%), níbe si ni awon perete ènìyàn yi o ti gba Ida ọgorùn-ún (100%), eyití Ọlorun Fe. Eyi tumọ si pe iwọ yoo gba ohun ti o ba lakaka fun. Ifokansi wa ti ko ni amulumala si ọrọ Ọlọrun ni o se afihan ifaraji wa  lati gba ohun ti a sọ fun wa ati idahun rere wa si ọrọ ti a gba eyi ti o tumọ si pe a ṣii okan wa paya fun Ẹmi Mimọ lati ṣiṣẹ ninu wa ati ki o si mu wa so eso nipa fifa ounkoun ti ko je  ti Ọlọrun tú  ni igbesi aye wa, ti o si gbin irugbin rere ti yio mu wa ri ojurere latodo baba.

ADURA
Baba orun Mo fe gba Ida ọgorùn-ún ohun ti O n fun wa. Ran mi lowo lati feti to ye si Oro Re, ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: 1 Tímótiu 4:12-16

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *