THE SEED
“But know this, that in the last days, perilous times will come:” II Timothy 3: 1 NKJV
The perilous time is indeed here; a time when the World is helplessly facing diverse crises, with the obvious truth of the second coming of our Lord Jesus Christ. Presently, a critical look at the happenings in the World reveal that everything that is manifesting this period has already been written by Apostle Paul. These days, people are more self-centered, proud, covetous, boastful, blasphemous, disobedient to parents and unholy, to mention but a few.
So much so that, the few that are standing for God have been greatly outnumbered, yet the word of God has not changed. It is important to note that if we are not walking in Godliness, we will be walking in ungodliness. It is not right to serve God and mammon together and still expect to make heaven. Such an idea is for double-faced, evil-doers who pretend to be believers but are against the truth. They hate the truth and do not want correction. Their minds are depraved, as far as faith is concerned. As true Christians, to escape from the perils of this time, we are expected to walk in the true doctrine of Christ, a purposeful life in faith, doing charity and being patient. If we are rooted in the doctrine of Jesus Christ and have the Holy Spirit in us, we cannot be easily influenced by any evil because we know the truth. More so, we cannot be easily deceived by heresy. Even when we pass through persecution because we believe in Jesus, we will still have hope of deliverance in Jesus Christ. However, Christians who are not rooted in the word of God will have no immunity and they will easily be deceived. Brethren, from the foregoing, let us study our scripture and be rooted in the word of God. In it, we will receive instructions and corrections, understand God’s doctrines guiding a true christian, so we can stand against evil machinations of these perilous times, and not fall victim.
BIBLE READING: 2 Timothy 3:2-5
PRAYER: O Lord God, my Father, uphold me with your right hand of righteousness that I may not perish with the World.
ÀKÓKÒ EWU WA NIBI!
IRUGBIN NAA
“Ṣugbọn mọ eyi pe ni awọn ọjọ ikẹhin, ìgbà ewu yoo de”. 2 Timoteu 3:1
Nitootọ akoko ewu naa ti de, akoko kan nigba ti agbaye nparun ti wọn ndojukọ awọn rogbodiyan oniruuru ati otitọ ti o han gbangba ni ti wiwa Oluwa wa Jesu Kristi nigba kejì. Ní báyìí, ṣíṣàkíyèsí àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nínú ayé fi hàn pé gbogbo ǹkan nípa àkókò yì nṣẹlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Àpọ́sítélì ́ Pọ́ọ̀lù ṣe kọ̀wé rẹ̀ tẹ́lẹ̀. Ní àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, àwọn ènìyàn yio túbọ̀ jẹ́ onímọtara-ẹni-nìkan, agbéraga, olojúkòkòrò, afunú, asọ̀rọ̀ òdì sí àwọn òbí àti aláìmọ́, kí a fi ẹ́nu ba díẹ̀, débi pé, àwọn díẹ̀ tí wọ́n dúró fún Ọlọ́run kò tíì pọ̀ to, ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kó yipada. O ṣe pataki lati ṣe akiyesi pe, ti a ko ba nrin nínú iwa-bi-Ọlọrun, ao máà rin nínú aiwa-bi-Ọlọrun. Ko tọ, lati sin Ọlọrun ati mammoni papọ, ki a sí tun nireti lati de ọrun. Irú èrò bẹ́ẹ̀ wà fún alágàbàgebè, aṣebi, tí ó nṣe bí ẹni pé òun jẹ́ onígbàgbọ́ ṣùgbọ́n tí ó lòdì sí òtítọ́. Wọ́n kórìíra òtítọ́, wọn kò sì fẹ́ ìbáwí. Ọkàn wọn ti sé bọ lòdì sí ìbámu igbagbọ. Gẹgẹbi awọn Kristiani tootọ, lati yọ ninu ewu akoko yii, a nireti lati rin ninu ẹkọ otitọ ti Kristi, igbesi aiye ti o ni ero ninu igbagbọ, ka ni ifẹ, pẹ̀lú sùúrù. Ti a ba fidimulẹ̀ ninu ẹ̀kọ́ Jesu Kristi ti a si ni Ẹmi Mimọ ninu wa, a kó lè tètè mú wa ṣé ohun búburú nitori a mọ otitọ. Pẹlupẹlu, ko le rọrun lati tán wa nipasẹ eke. Paapaa nigba ti a ba nla inunibini kọjá nitori a gbagbọ ninu Jesu, aò tun ni ireti igbala ninu Jesu Kristi. Bí ó ti wù kí ó rí, àwọn Kristẹni tí kò fìdí múlẹ̀ nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kì yió ní àjẹsara, a ó sì tètè tàn wọ́n jẹ. Ẹ̀yìn ará láti ìsinsìnyí lọ ẹ jẹ́kí a máa kọ ẹ̀kọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ki a sí jinlẹ nínú rẹ.̀ Nínú rẹ̀, a ó gba ìtọ́ni àti àwọn àtúnṣe, a o máa lóye ẹ̀kọ́ rere, ìwàláàyè òdodo àti àwọn ìwà rere mìíràn kí a ba lè dojú- ìjà kọ, àwọn ibi tí ó wà ní àkókò éwu náà, kí a má sì jẹ́ alábápín nínú ijìyà naa.
BIBELI KIKA: 2 Tímótì 3:2-5
ADURA: Oluwa Ọlọ́run Baba mi, fi ọwọ ọtún ododo Rẹ̀ gbe mi soke ki emi ki o ma ba ṣègbé pẹ̀lú aye.