THE SEED
“But at midnight Paul and Silas were praying and singing hymns to God, and the prisoners were listening to them. Suddenly there was a great earthquake, so that the foundations of the prison were shaken; and immediately all the doors were opened and everyone.
Praising God is not option for Christians, it is part of us at all times.
When you learn to praise God when things are not looking good, you become a threat to the whole of hell. There is no better way to frustrate the enemy of your soul than to praise God. The devil always tries to keep us grumbling and complaining at midnight hour. He wants praise and gratitude to be the farthest thing from our hearts and minds. But the truth is, when you praise God at trying times, your breakthrough becomes unstoppable. Paul and Silas had this secret. They praised God at the most difficult time (Acts 16:25). Then they had a most glorious visitation. Are you experiencing trying times? Do not grumble. Just praise the Lord of heaven. Your breakthrough is around the corner.
BIBLE READING: Psalm 34:1 – 4
PRAYER: Oh Lord, your praises will not seize in my life.
AGBÁRA NÍNÚ ÌYÌN
IRUGBIN NAA
“Ṣugbọn làrin ọ̀ganjọ́ Paulu oun Sila ngbadura, wọn sì nkọrin sí Ọlọrun: awọn ará túbú sí ntẹti sí wọn. Lojiji iṣẹlẹ nlá sí ṣẹ, tobẹ ti ipinlẹ ile túbú mí titi: lọgan gbogbo ilẹkùn ilé túbú sí ṣi, ide gbogbo wọn sí tú silẹ.” Iṣe awọn Àposítélì 16:25-26.
Yin yin Ọlọrun Kii ṣe ohun ai gbọdọ maṣe fun Onigbagbọ. O jẹ dandan fún wa ni gbogbo igba. Nigbati o ba kọ̀ lati yin Ọlọrun nigbati awọn nkan ko lọ dede, o jẹ ewu si gbogbo ọrun apadi. Ko si ọna ti o dara lati fún awọn ọta ọkàn rẹ ni ijaya, ju lati yin Ọlọrun lọ. Eṣu ngbiyanju nigbagbogbo lati jẹ ki a kùn sí Ọlọ́run ati ṣe awawi ni wakati ọganjọ. Ó fẹ́ kí ìyìn àti ìmoore jẹ́ ohun tí ó jìnnà réré julọ si ọkàn àti èrò inú wa. Ṣugbọn otitọ ibẹ ni pe nigba ti o ba nyin Ọlọrun, ni awọn akoko ipenija, aṣeyọri rẹ di eyiti a ko le da duro. Pọ́ọ̀lù àti Sílà ní àṣírí yìí. Wọn yín Ọ́lọ́run ní gba ìṣòro wọn (Iṣe Awọn Àposítélì 16:25 ) Lẹhin eyi wọn ni ibapade ti o logo. Ṣe o wa ni akoko idanwo rẹ? Maṣe kùn. O nilo lati yin Oluwa ọrùn. Alaja rẹ wà ni itòsí.
BIBELI KIKA: Sáàmù 34:1-4
ADURA: Oluwa, iyin rẹ koni tan laye mi.