THE REWARDER

THE REWARDER
THE SEED
“And Israel said to Joseph, I had not thought to see thy face: and, lo, God hath shewed me also thy seed.” – Genesis 48:11 (KJV)

God delights in rewarding His children, often in ways that exceed their expectations. Israel never imagined seeing Joseph again, yet God not only reunited them but also blessed him to see his grandchildren. That is the nature of our rewarder—He surprises the faithful with abundant blessings. As children of God, our focus must remain on diligently seeking Him and walking in obedience to His will. In due time, He will reward faithfulness with blessings that surpass human imagination. His timing may not always align with ours, but His reward is always perfect.

BIBLE READINGS: Hebrews 11:6–12 (KJV)
PRAYER: The Just Rewarder, give me grace to diligently walk in Your will. Let my life reflect Your favour and faithfulness, in Jesus’ name. Amen.

OLUSAN ESAN
IRUGBIN NAA
Israeli si wi fun Josefu pe, Emi kò dába ati ri oju rẹ mọ́: si kiyesi i, Ọlọrun si fi irú-ọmọ rẹ hàn mi pẹlu. Genesis 48:11

O dun mo Olorun ninu lati maa san esan fun awon omo re, ni awon ona ti o koja ireti won. Isreali o lero lati tun ri Josefu mo, sibe, Olorun ko tile mu won pade ara won nikan, o tun bukun fun lati ri awon omo omo re. Bi Elesan wa ti ri ni eyi- O ma nya awon olododo lenu pelu ekunrere Ibukun.
Gegebi omo Olorun, Ifojusun wa gbodo wa sibe lori wipe ki a maa waa, ki a si maa rin ninu igboran si ife re. Ni akoko ti o to, yio san esan isododo pelu Ibukun ti o koja ero eniyan. Asiko re le ma papo mo tiwa sugbon, esan re ma nje pipe.

BIBELI KIKA: Heberu 11:6-12.
ADURA: Elesan otito, fun mi ni oore ofe lati rin ninu ife re. Jeki aye mi se afihan oju rere re ati otito re ni oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *