THE SEED
“For by grace are ye saved through faith; and that not of yourselves: it is the gift of God.” Ephesians 2:8 (KJV)
True transformation is not just about changing habits but becoming a new creation in Christ. This change begins with faith. It is by faith that we receive the grace of God, step into a relationship with Christ, and walk in obedience to His will. Faith connects us to the life-changing power of God. It is the bridge between our old nature and the new life Christ offers. As we believe His Word, our hearts and minds are renewed, and we find the strength to let go of old habits, toxic relationships, and familiar mindsets that hold us back. Transformation is a process, and faith sustains us through it. It reminds us of our true identity as children of God, loved, redeemed, and called for a purpose. Let faith be the foundation of your transformation today.
BIBLE READING: Hebrews 11:18
PRAYER: Lord, thank You for the transforming power of faith. Help me to trust You completely and to walk in obedience, even when the path is unclear in Jesus’ name, Amen.
IPA TI IGBAGBỌ KO NÍNÚ ÌYÍPADÀ ÀGBÀYANU
IRUGBIN NAA
“Nítorí oore-ọfẹ lí a fí gbà yin la nipa igbagbọ; àti èyíinì kí ṣé ẹ̀yìn ti karayin: ẹ̀bùn Ọlọ́run ni.” Éfésù 2:8
Iyipada otitọ kii ṣe nipa iyipada awọn iwa ṣugbọn nípa jíjẹ ẹda titun ninu Kristi. Iyipada yi bẹrẹ pẹlu igbagbọ. Nipa Igbagbọ ni a gba oore-ọfẹ Ọlọrun, ti a sí tẹsiwaju sinu ìbáṣèpọ pẹlu Kristi, ati rìnrìn nínú igbọràn si ifẹ Rẹ . Igbagbọ so wa pọ mọ agbara iyipada nínú Ọlọrun. O jẹ afara laarin ẹda wa atijọ ati Igbesi aye tuntun ninu Kristi tí ó fífún wa. Bí a ṣe gba ọ̀rọ̀ rẹ̀ gbọ́, ọkàn wa àti èrò wa, ti di tuntun, tí a sì rí agbára láti lọ kúrò nínú àwọn àṣà àtijọ́, àti iwa ìbàkẹgbẹ pọ iwa burú burú, àti èrò inú tí a mọ̀ pé ó le dá wa dúró.Iyipada jẹ ilana ati Igbagbọ ti o n gbe wa ro nipasẹ rẹ .O rán wa leti idanimọ otitọ wa bi awọn ọmọ Ọlọrun ti a fẹ, ti a ràpada ti a pe fun idi kan. Jẹ ki igbagbọ jẹ ipilẹ iyipada rẹ loni.
BIBELI KIKA: Hébérù 11:18
ADURA: Olúwa mo dupẹ fún iyipada agbára igbagbọ. Ràn mí lọwọ láti gbẹkẹle Ọ patapata àti láti máa rìn nínú ìgbọràn, bí ó tilẹ jẹ pe ọ̀nà náà kó lọ tààrà ni orúkọ Jesu Amin.