The Unsatisfied Eater

 

THE UNSATISFIED EATER

THE SEED 

“Can I forget any longer the treasures of wickedness in the house of the wicked, and the  scant measure that is accursed? Shall I acquit the man with wicked scales and with a bag  of deceitful weights?” Micah 6:10-11 ESV 

According to words from the Holy Spirit, the unrighteous shall harvest, eat and not be  satisfied, but the righteous shall harvest, eat and will be satisfied.  

What is your work? It may seem getting away with unfaithfulness or defrauding others  to live a luxurious life is materially profitable now, but have we ever wondered why there is no  peace and satisfaction for such people? It’s in accordance with God’s judgement in Micah 6:14  “You will eat but not be satisfied; your stomach will still be empty, you will store up but save  nothing, because what you save, I will give to the sword”. 

God is just in all His ways; He will not acquit the man with wicked scales and with a bag  of deceitful weights. Brethren, there are abundance of situations, messages, and influences  that can persuade us to do evil, but it is wise to reject the devil and his suggestive acts of  wickedness totally. Give your life to Christ to enjoy satisfaction in your endeavours and always  remember that God will not withhold anything good from those who walk uprightly. Ps 84: 11.

PRAYER 

Lord, help me to live righteously and be satisfied with my life. 

BIBLE READINGS: Micah 6:9-16 

ALAINI ITELORUN, OJEUN 

IRUGBIN NAA 

“Isura iwa buburu ha wa ni ile eniyan buburu sibe, ati osuwon aikun ti o je ohun ibinu? Ki  emi ha ka won si mimo pelu osuwon buburu, ati pelu apo osuwon etan?.” Mika 6:10-11 Gege bi oro ti o ti enu Emi Mimo jade, eniyan buburu yio kore, yio jeun, on ki yio si yo,  sugbon olododo yio kore, yio jeun, yio si ni itelorun.  

Kini ise re? o le dabi eni pe iwa aisododo tabi iloni lowo gba nitori ati gbe igbe aye irorun  lere lowolowo, sugbon, nje a ti woye idi ti ko fi si alafia ati itelorun fun iru awon eniyan bayi. Eyi wa ni ibamu pelu idajo Olorun ninu iwe Mika 6:14, ‘iwo yio jeun, sugbon iwo ki yio yo,  idabe yio wa laarin re, iwo o ko kuro sugbon iwo ki yio lo lailewu ati eyi ti ko lo li emi o fi fun ida’ Olotito ni Olorun ni gbogbo ona re. ki yio da enia buburu ati eletan lare. Eyin ara,  opolopo isele, atejise, ati oro iyini lokan pada si ohun buburu ni o wa. Sugbon, o dara ki a maa fi  esu ati gbogbo iwa buburu ti o nfi si wa lokan lojoojumo bu. 

Fi aye re fun Jesu, ki o le ni itelorun ni gbogbo ona aye re, ki o si maa ranti wipe, Olorun  ki yio fawo ohun rere seyin lodo awon eni iduro sinsin. Orin Dafidi 84:11. 

ADURA 

Oluwa, ran mi lowo ki n le gbe igbe aye ododo, ki n si ni itelorun pelu aye mi. Amin 

BIBELI KIKA: Mika 6:9-16

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *