THE URGENT INVITATION

THE URGENT INVITATION

THE SEED

“While it is said, To day if ye will hear his voice, harden not your hearts, as in the provocation.” – Hebrews 3:15 (KJV)

 

Jesus Christ offers an urgent invitation to all. In Luke 14, the master prepared a great feast and invited many, but they made excuses. So, he called others to fill his house. God is still inviting people to come to Him—today. Tomorrow is not guaranteed. Now is the time to surrender to Christ and accept His gift of salvation. This is an invitation to eternal life. Don’t ignore His call or harden your heart.

BIBLE READINGS:  Luke 14:15–24 (KJV)

PRAYER: Lord Jesus, come into my heart today. I confess You as my Lord and Saviour. Strengthen me to forsake sin and follow You faithfully. Amen

IFIWEPE NI KIAKIA

IRUGBIN NAA

Nigbati a nwipe, Loni bi ẹnyin bá gbọ́ ohùn rẹ̀, ẹ máṣe sé ọkàn nyin le, bi igba imunibinu. Heberu 3:15

Jesu Kristi fi iwe pe gbogbo eniyan ni kiakia. Ninu iwe Luku14, Okunrin kan se ase, o si pe opolopo eniyan, sugbon won wa awawi. Torina, o pe awon elomiran si ile re. Olorun shin pe awon eniyan lati wa si odo re- Loni. Ko si idaniloju fun ola. Nisisinyi ni asiko lati jowo oun gbogbo fun Kristi, ki a si tewo gba ebun igbala re. Eyi je ipe si iye ayeraye. Ma se ko eti ikun si ipe re tabi ki o se aya re le.

BIBELI KIKA: Luku 14:15-24

ADURA: Jesu Oluwa. Wa sinu okan mi loni. Mo jewo re ni Oluwa ati olugbala mi. fun mi ni agbara lati ko ese sile ati lati to o lehin lododo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *