THE SEED
“Enter through the narrow gate. For wide is the gate and broad is the road that leads to destruction, and many enter through it.” — Matthew 7:13 NIV
Jesus is the only way to eternal life. The narrow path requires sacrifice, commitment, and focus, but it leads to everlasting joy. The broad way is easy and attractive but ends in destruction. Walking the narrow path may not always be popular or convenient, but it is the path of purpose, purity, and peace with God. Every step taken in obedience brings you closer to eternal glory. Don’t be discouraged by how few walk this way—God’s grace will sustain you. Fix your eyes on Jesus, not the distractions around you. Stay faithful on the narrow way that leads to life.
BIBLE READINGS: John 14:1–6; Matthew 7:13–14
PRAYER: Jesus, guide me through the narrow way that leads to eternal life. Amen.
ÒṆÀTÍÓTÓḲA SÍÌYÈ
IRUGBIN NAA
“Ẹ ba ẹnu-ọ̀nà tóóró wọlé; gbòòrò ni ẹnu- ọ̀nà náà, àti oníbùú ni ojú ọ̀nà náà tí ó lọ sí ibi ìparun, ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ ni àwọn ẹni tí ń bá ibẹ̀ wọlé. Matiu 7:13
Jésù nikan ni Ona si iye ainipekun. Ona tooro naa pè fun irubo, if’ara eni ji ati
afokansi sugbon o lo si ayo ayeraye. Ona gbooro naa rorun, o fanimora sugbon opin re iparun ni. Ririn ni ona tooro naa le ma wuyi tabi rorun sugbon oun ni ona si ipinnu, iwa mimo àti alaafia pelu Olórun. Gbogbo igbesẹ ti a ba gbe ninu igboran n mu o sunmo ogo ayeraye. Má se rewesi nipa iye awon kereje ti n rin ni ona yii- oore-ofe Olórun yio di o mu. Teju mo Jésù, kii se awon bii kamikami ti o wa ni ayika re. Je olotito ni ona tooro yii ti o lo si iye.
BIBELI KIKA: Johanu 14:1-6; Matiu 7:13-14.
ADURA: Jésù, tó ̣mi lati gba ona tooro ti o lo si iye ainipekun. Amin.