TRUST HIS LEADING THE SEED

TRUST HIS LEADING THE SEED
“…while Paul chose Silas and left,
commended by the believers to the care of the Lord’s grace.” — Acts 15:40 GNB
God doesn’t always give us a loud, clear sign before we take a step of faith. Sometimes, He leads us quietly through inner promptings and right positioning. Silas stayed back in Antioch without knowing God was arranging his next assignment. Trusting God’s leading means surrendering control, even when you can’t see the full path. Divine direction often unfolds step by step, not all at once. When your heart is aligned with His will, every step becomes a setup for destiny. We must learn to trust God’s leading, even when the full picture is not clear. Aligning our motives with His will positions us for divine opportunities.
BIBLE READINGS: Acts 15:33–41
PRAYER: Heavenly Father, I trust You to guide me even when I don’ t fully understand. Amen.

GBA IDARI RE GBO
IRUGBIN NAA
ṢugbọnPauluyànSila,osilọ,biatifiilé ore-ọfẹ Oluwa lọwọ lati ọdọ awọn arakunrin. Ìse Àwon Aposteli 15:40
Olórun kii saba fun wa ni amin alariwo ti o han gbangba ki a to gbe igbese igbagbo. Leemiran, O maa n rora dari wa nipa ero kelekele ati mimu wa si ipo ti o to.̣ Sila duro ni Antioku lai mo pe Olórun n ś’eto ise re titun. Gbigbagbo ninu idari Olorun tumo si jijowo idari ara eni bí o ko tile ri ona ni
ekunrere. Idari emi maa n farahan ni sị́sèntèḷé kii se leekan naa. Ti okan re ba wa
ni ibamu pelu ife Re si o, gbogbo igbese re yio di ateg̣ un si ayanmo re. A ni lati ko ̣ lati ̀̀̀ ́ gbagbo ninu idari Olorun bí ekunrere aworan naa kò ba tile tii farahan. Jije ̣ ki ́́
erongba wa wa labe ife Re fi wa si ona abayori ti emi.

BIBELI KIKA: Ise Awon Aposteli 15:33- 41

ADURA: Baba wa ni Orun, mo gbagbo ninu re lati to mi sona bí emi ko ba tile ni oye ni ekunrere. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *