WHAT IS YOUR SONG

THE SEED

“Then sang Moses and the children of Israel this song unto the Lord and spake saying, will sing unto the Lord for he hath triumphant gloriously the horse and his rider hath he thrown into the sea.” Exodus 15:1

What do you want God to do that He has not done? can you look back and see many people that you started the race with and  see where they are on today? what is your song to the Lord? Many are singing the songs of complain and some are asking questions of what their tomorrow will bring, but for you and your family, He has promised you a great and beautiful future. (Jeremiah 29 : 11). And what is your song to the Lord. Our God is not a man, that He should lie, neither the son of man that He should repent hath he said, and shall not do it? Or hath He spoken and shall He not make it good? Numbers 23 : 19, brethren as you have spoken in His ears so shall He do unto you and so what is your song?.

BIBLE READING: Psalm 34 : 1 – 2

PRAYER: Oh Lord receive my praises everyday

KÍNÍ ORIN RẸ

IRUGBIN NAA

“Nigbana ni Mósè àti àwọn ọmọ Israẹli kọ orin yí sí Olùwà wọn wípé, Èmi o korin sí Olùwà, nitoriti o pọ li ògo: ati ẹṣin àti ẹlẹ́sìn ni o bí ṣubú sinu okun.” Eksodu 15:1

 

Kini o fẹ ki Ọlọrun ṣé ti ko tí i ṣe? ṣugbọn ṣe o le wo ẹyin wò ki o si ri ọpọlọpọ àwọn eniyan ti ẹ jọ bẹrẹ ere ije titi di oni, ati kini orin yin si Oluwa? Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ń kọ orin ìkùnsínú, àwọn kan sì ń béèrè ìbéèrè nípa ohun tí ọ̀la wọn yió ṣe rí; ṣùgbọ́n fún ìwọ àti ìdílé rẹ Ó ti ṣèlérí ọjọ́ ọ̀la ńlá tí ó sì lẹ́wà, Jeremiah 29:11 àti kí ni orin rẹ sí Olúwa. Ọlọrun wa ki i ṣe enia, ti yio fi purọ, bẹ̃ni ki i ṣe ọmọ-enia ti yio fi ronupiwada njẹ O ti sọ ati pe ki yio ṣe e?  Tàbí ó ti sọ̀rọ̀ tí kò sì ní mú un ṣẹ?  Numeri 23:19, Ẹ̀yin ará, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti sọ ní etí rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni yóo ṣe sí yín, nitori ìdí èyí  kí ni orin yín.

BIBELI KIKA: Saàmù 34:1-2

ADURA: Oluwa gba iyin mi lojojumo.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *