When Not To Sleep

THE SEED
A little sleep, a little slumber, A little folding of the hands to rest. Proverb 24:33.

As we all know that sleep is very essential to humans, there are however some situations that we should not be sleeping. Individuals that operate all forms of machines for example vehicles, construction machines, factory machines, etc. should not be sleeping when at work. When we have the audience of a very important personnel like Kings, governor and President, we don’t sleep. Likewise, and much more, when we are praying to Almighty God, when we listen to the word of God being preached and when God is speaking to us, we should not be found sleeping. A soldier at war do not sleep because the enemy can be at the corner. Spiritually, Christian should not be found sleeping because the devil is at constant war with us.

PRAYER
May I have the strength not to be sleeping when am not supposed to in Jesus name. Amen.
BIBLE READINGS:  Proverb 19:15, Proverb 6:9, 1 Thessalonians 5:6, Acts 20:9-12.

 IGBA AISUN

IRUGBIN NAA
Oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi. Owe 24:33

Gege bi a se mo, orun se Pataki si eniyan, sibe awon igba kan wa ti a gbudo wa ni aisun. Eni to ba n wa oko tabi ti o n fi ero irin sise ko gbudo sun lenu ise. Nigba ti a ba wa ni iwaju awon eniyan jankanjankan bii oba, gomina tabi aare, a kii sun. Ko to ki a ma sun nigba ti a ba n gbadura, tabi ni akoko iwaasu, nigba ti Oluwa n ba wa soro. Jagunjagun o gbudo sun loju ogun nitori wipe ota le w ani koro. Ninu emi, Kristeni o gbudo sun nitori satani kii siwo ogun pelu wa.

ADURA
Oluwa, fun mi ni agbara lati wa ni aisun nigba ti ko ye kii sun, ni oruko Jesu. Amin
BIBELI KIKA: Owe 19:15, Owe 6:9, 1 Tessalonika 5:6, Ise Awon Aposteli 20:9-12.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *