THE SEED
“Now therefore hearken unto me, O ye children: for blessed are they that keep my ways.”
Whether we acknowledge or not voices are constantly speaking to us spiritually and physically, then the voice we listened to is either to help, harm and even kill us, it means we all follow a voice of some kind, we all know which voice we reference for final authority. We all listen to someone, whether it be just ourselves, another human authority, or God as revealed through His word, we are talking about the ultimate voice of authority that people follow. Whose voice do we follow? and do we truly know the voice of the Lord?
Listen for God’s voice in everything you do, everywhere you go; He’s the one who will keep you on track, don’t assume that you know it all. Run to God, run from evil.
Children of God has to follow the voice of God and Jesus because they know their voice. He is the one that has the final say at the point of authority in all areas of our lives. No other voice can match His or carry His power. Brethren, we should all understand that following after other voices is following after strangers and thieves who, if followed, will steal, kill, and destroy our souls. Jesus came to give abundant life. He came with divine authority and purpose. He is the door to salvation; He is the good shepherd who gave His life for the sheep. Therefore, we should hearken to the voice of God and Jesus, so for the Abundant blessings of God over all that concerns us to be granted.
BIBLE READING: Proverbs. 3: 5 – 11
PRAYER: Oh Lord my creator, Father grant me a listen ear to your voice at every stage of my life so not to miss my steps in Jesus Mighty Name. Amen.
OHUN TA NI O N GBO?
IRUGBIN NAA
“Njẹ nitorina ẹ gbo temi, ẹnyin ọmọ: nitori ibukún ni fun awọn ti npa ona mi mo.” Òwe 8:32
Boya a mo tàbí a ko mo, awon ohun ma n ba wa sọrọ nigbagbogbo ni Ẹmi ati ti ara. Lẹhinna
awon oun ti a gbọ le ranwalọwọ, pawalara ati paapaa o le pa wa, o tumọ si pe oniruru ohun kan naa ni gbogbo wa n tele, gbogbo wa mọ iru ohun ti a n bowo fun nipa ti owo. Gbogbo wa ni a gbọ ti ẹnikan, boya o jẹ ara wa nikan, aṣẹ eniyan miiran, tabi Ọlọrun bi a ti fi han nipasẹ ọrọ Rẹ, a n sọrọ nipa ohun ti o ga julọ ti aṣẹ ti awọn eniyan tẹle. Ohùn ta ni a tẹle? Awa si mo ohùn Oluwa nitõtọ? Gbọ ohùn Ọlọrun ni ohun gbogbo ti o n se, nibikibi ti o ba lọ; on ni yio mu ese re duro. Ma se ro pe o mọ gbogbo oun tan. Sa to Olorun! Sa fun Esu. Awọn ọmọ Ọlọrun ni lati tẹle ohùn Ọlọrun ati Jesu nitori wọn mọ ohun wọn. Oun ni ẹni ti o ni ase. Ko si ohun miran ti o dabi tire, ko si si eleyi ti o ni agbara bi tire. Ará, ó yẹ kí gbogbo wa mo pé títelé àwọn ohùn mìíràn dabi títelé àwọn àjèjì àti àwọn ọloṣà tí won n jalè, tí wọn paeniyan,tí wọn yóò sì pa emí wa run. Jesu wa lati fun wa ni iye lọpọlọpọ. Ó wá pelú ọlá àṣẹ àti ète àtorunwá. Oun ni ilekun igbala; Oun ni oluṣọ-agutan rere ti o fi ẹmi re fun awọn agutan. Nítorí náà, a gbodo tetí sí ohùn Ọlorun àti Jésù, nítorí náà, kí ìbùkún Ọlorun tó po yanturu le je Tiwa.
BIBELI KIKA: Owe 3:5-11
ADURA: Oluwa Eleda mi, Baba je ki n gbo ohun re ni gbogbo ipele aye mi ki n mase padanu igbese mi loruko Jesu Alagbara. Amin.