With God All Things Are Possible

THE SEED
“And Jesus looking upon them saith, With men, it is impossible, but not with God: for with God all things are possible.” Mark 10:27

If you had seen the earth in its initial state, you would have concluded that there was certainly no possibility of anything good coming out of it. Surprisingly, in less than seven days, the Almighty God created one of the greatest beauties out of nothing. God shut the mouths of lions for Daniel. God use Mordecai to change the name of Hadassah the slave girl to Esther the Queen. God turned a flaming furnace into an air-conditioned atmosphere for three Hebrew boys: Shadrach, Meshach, and Abednego. The Almighty God pulled down the wall of Jericho standing in the way of the people of God. What can God not do? Don’t ever doubt God’s ability to make the impossible possible in your life. No matter what you are going through, our God-the Maker of all things – can turn it around. You have to commit your life to His hands and trust Him for the victory that He will give to you.

PRAYER
Father, grant me victory in my life endeavours because I believe that you can do all things according to your will.
BIBLE READINGS:  Romans 4:16-24

 PELU ÓLORUN, OHUN GBOGBO NI SISE

IRUGBIN NAA
“Jesu si wò wọn, o wipe, Fun eniyan, ko ee e, ugbọn kii e fun Ọlọrun: nitori ohun gbogbo ee e fun Ọlọrun.” Marku 10:27

Kani o ri bi aye se ri ni ibeere pepe, Iwo yio so wipe, ko si oun rere kan ti o le ti Inu re jade wa. Iyalenu ni wi pe ko tii ju ojo meje lo, Olorun eledumare da okan lara awon ewa to tobi julo ninu ofo.Ọlọrun di ẹnu awọn kiniun fun Danieli. Ọlọ́run lo Módékáì láti yí orúkọ Hádásà, ẹrúbìnrin náà padà sí Ẹ́sítérì ayaba. Ọlọ́run yí Ina ìléru tó ń jó pada si ayika ti o tutu fún àwọn ọmọkùnrin Hébérù mẹ́ta: Ṣádírákì, Méṣákì, àti Àbẹ́dínígò. Ọlọrun Olodumare wó odi Jeriko lule tí ó dúró ní onà àwọn ènìyàn Ọlọrun. Kí ni Ọlọ́run kò lè ṣe? Maṣe fi ígba kankan ṣiyemeji nipa agbara Ọlọrun pe oun ti ko ṣee ṣe le e di sise ninu igbesi aye rẹ. Ohun yòówù ti o le ma a la koja, Ọlọ́run wa, Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo, lè yí i padà. O ni lati fi ẹmi rẹ le ọwọ Rẹ ki o si gbẹkẹle e fun iṣẹgun ti Oun yoo fi fun ọ.

ADURA
Baba, fun mi ni iṣẹgun ninu awọn igbiyanju igbesi aye mi nitori mo gbagbọ pe o le ṣe ohun gbogbo gẹgẹbi ifẹ rẹ.
BIBELI KIKA: Róòmù 4:16-24

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *