THE SEED
A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies”. Proverbs 31: 10(NIV).
A woman of noble character is honest, hardworking, trustworthy and wise like Ruth, she is loyal and dependable striving to serve the Lord. She is the type of woman who makes smart, wise decisions by relying on the wisdom that comes from above. She is gracious, merciful, kind and submissive to her husband. While we know there is no perfect person other than Jesus himself. Some people can be called a wife of noble character as Boaz called Ruth a woman of noble character. Ruth chose to stay with her mother-in-law Naomi, after the death of her husband and resettle in a foreign land far from her people. Ruth behaved in an upstanding and morally righteous manner and worked hard in the fields to provide for Naomi. Therefore, a woman of noble character is strong and courageous, she worries less about the future, speaks with wisdom, do not gossip or idle chatter and sensibly teaches those under her care. Very helpful while providing for her husband, and She ensures there’s adequate clothing for everyone in her household not only her children and husband but those she employs and everyone around her, she dresses well too. Most importantly, she fears the lord, So, let us all strive to be like the wife of a noble character described in Proverbs 31; hardworking, selfless, compassionate, strong, merciful and kind.
BIBLE READINGS: Proverbs 31:10-15
PRAYER: Jesus, give me the grace to become a person of noble character in Jesus’ name. Amen.
Monday, September 23, 2024
OBÌNRIN ONÍWÀ RÉRÉ
IRUGBIN NAA
“Tani yio ri obìnrin oníwà réré? nítorí ti iye rẹ̀ kọjá iyùn.” Iwe Òwe 31:10
Obinrin oníwà réré jẹ olotitọ, oṣiṣẹ, alaapọn ati ọlọgbọ́n gẹgẹ bi Rutu, o jẹ olootọ enití o ṣe e gbẹkẹle, ti o ngbiyanju lati sin Oluwa. O jẹ́ iru obinrin ti o lé ṣe ipinnu ti o mu ọgbọn dání, nipa gbigbe ara le ọgbọ́n, ti o ti oke wá. O jẹ oloore-ọfẹ, aṣóore , ati o ni tẹriba fun ọkọ. Ni wọ́n ìgbà tí a mọ̀ pé kò sí ẹnì pipe kan a fi Jesu funrarẹ. Diẹ ninu awọn eniyan ni a le pe ni iyawo oniwa réré; gẹgẹbi Bóásì ṣe pé Rúùtù ni obìnrin oníwà réré. Rutu yan lati duro pẹlu iya-ọkọ rẹ̀ lẹhin ikú ọkọ rẹ, o tun yàn láti gbé ni ilẹ ajeji ti o jinna si awọn eniyan rẹ̀. Rutu huwa ti o tayọ ti o si farawe ọ̀nà òdodo, nípa ṣíṣe iṣẹ kárakára nínú oko lati pese fun Náómì. Nitorina obirin ti o ni ìwà réré jẹ alagbara ati onigboya, ti o ko ṣé aniyan rárá nipa ọjọ iwaju, enití nsọrọ pẹlu ọgbọn, kii ṣe ofofo tabi sọrọ asan, ati olukọ àwọn tí wọn wa ní abẹ ìtọ́jú rẹ̀. Oluranlọwọ ti o péye lakoko ti o npèsè fun ọkọ rẹ, ẹnití o nrii daju pe aṣọ ti o peye wa fun gbogbo eniyan ninu ile rẹ kii ṣe awọn ọmọ ati ọkọ rẹ nikan, ṣugbọn gbogbo eniyan ti o wa ni ayika rẹ, o máà nwọ aṣọ daradara pẹ̀lú. Ni pataki julọ o bẹru Oluwa, nitori naa ẹ jẹ ki a sa ipa lati dabi iyawo oniwa réré ti a ṣapejuwe rẹ ninu iwe owe 31; enití o ńṣe iṣẹ kárakára aláìmọtara-ẹni-nìkan, òní- yonu, alágbára, alaanu àti onínúure.
BIBELI KIKA: Iwe Òwe 31:10-15
ADURA: Jesu fun mi ni oore-ọfẹ lati jẹ eniyan oniwa réré lórúkọ Jesu Àmín.