THE SEED
“…He commanded them to take nothing for the journey except a staff—no bag, no bread, no copper in their money belts…” Mark 6: 8 NKJV
Is God telling us not to plan for the future? No, He isn’t. Jesus Christ is demonstrating to you and me here that God is able and willing to provide everything we need along the way to fulfilling our God-given mission in life. God can be trusted to help us when we are doing the right thing. He will always make a way for you and me. Only ensure that the thing you are doing is what He wants you to do. Our ability to obey His instructions concerning our given mission is the beginning of our success. Each mission has its set of instructions, on how one should approach it to accomplish God’s intention. As a student and a believer, the Holy Spirit can instruct you on where to study to pass your test or examination which might not be a popular choice this is God’s intentional provision for you to be fruitful without much labour. There is always God’s provision that comes with instructions to accomplish our missions and tasks in life, all we need to do is to trust God and do as we are told to be able to enjoy the divine provision.
PRAYER
Heavenly Father I trust You to provide for me, in Jesus’ name Amen.
BIBLE READINGS: Mark 6:7-12 NKJV
O LE GBEKE LE
IRUGBIN NAA
O sọ fún wọn pé, wọn kò gbọdọ̀ mú ohunkóhun lọ́wọ́, àfi ọ̀pá ìtìlẹ̀ wọn. Wọn kò gbọdọ̀ mú oúnjẹ, àpò ìgbànú, tàbí owó lọ́wọ́. Máàkù 6:8 MKJV
Ṣé Ọlorun sọ fún wa pe ki a ma se ni imurasile fun ojo ola? Rara, Oun kii ṣe bẹ. Jesu Kristi n ṣe afihan fun iwọ ati emi nihin pe Ọlọrun ni agbára, o si Fe lati pese ohun gbogbo ti a nilo bi a se n lakaka wipe ki erongba Ólorun se nínú aye wa. A lè fọkàn tán Ọlorun pé yóò ràn wá lowo nígbà tá a bá ń ṣe ohun tó to. Oun yoo la ọna fun iwọ ati emi ni gbogbo ígba. Sa a ri daju pe ohun ti o n ṣe ni ohun ti O fẹ ki o ṣe. Ibere aseyori wa ni gbigboran si ìtoni re eyi ti o je mo Iṣẹ ti o gbe le was lowo. Ise kọọkan lo ni awọn itosona re Lori bi ènìyàn yi o se se lati mu erongba Ólorun se. Gege bí akekoo àti onígbàgbo, Ẹ̀mí Mímo lè to o sona lori ibi tí o ti lè kekoo láti yege ìdánwò tàbí ìdánwò rẹ tí ó lè má je oun ti opoplopo Yan Lati se, sugbon eleyi ni ife Ólorun fun o laise laala. Ipese Ọlọrun nigbagbogbo wa pelu itosona re la ti mu wa ṣaṣeyọri nínú aye. Gbogbo ohun ti a nilo lati ṣe ni lati gbẹkẹle Ọlọrun, ki a si se gẹgẹ bi a ti pase fun wa ki a le gbadun ipese atọrunwa naa.
ADURA
Baba orun Mo gbekele O lati pese fun mi, ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Mk. 6:7-12 NKJV