The Source Of Truth

THE SEED
“Then you will know the truth, and the truth will set you free.” John 8:32

Truth, what is it? An English poet, Robert Browning once said “I yearn for truth, but shall not reach it till I reach the source”. Truth is believing with evidence. Freedom is achievable by the knowledge of truth. But what is the source of truth for Christians? Many people believe in words of mouth from friends and social media. The world is riddled by social media sharing worldly beliefs than the Word of God. John1: 1 says “In the beginning was the Word, and the Word was with God, and the Word was God.” Tailor yourself towards the real source of truth which is the Word of God, the Bible. Be ready to share the source and lead others to the living water. In John 4, the woman at the well met Jesus and she went to call others to the Source. Are you willing to do so too?

PRAYER
Father, teach me to humbly share the source of truth with others.
BIBLE READINGS: John 8:31-47

ORISUN OTITO

IRUGBIN NAA
“E o si mo otito, otito yio si so yin di ominira.” Johannu 8:32

Otito. Kinni Otito? Arakunrin akewi, Robert Browning so nigbakan wipe “mo n fe otito, sugbon n ko le rii titi n o fi de orisun re”, otito ni gbigbagbo pelu idaniloju. A si le di ominira nipa mimo otito. Sugbon, kinni orisun otito fun Kristeni? Opolopo a maa gba oro enu ore gbo ati oro ori ayelujara. Aye ti di ti ayelujara ti won ti n so ohun ti aye ju bi won ti n so ti Olorun. Johannu 1:1 wipe “Li atetekose li oro wa, oro si wa pelu Olorun, Olorun si li oro naa.” Fa okan re sunmo ibi orisun otito ti nse oro Olorun, Bibeli. Setan lati fi orisun naa han ki o si dari awon eniyan si ibi omi iye. Ninu Johannu 4, obinrin ti o wa leti kanga ba Jesu pade, o si lo pe awon iyoku wa si ibi orisun. Iwo ha setan lati se bee naa.

ADURA
Ko mi ki nle fi orisun otito han awon eniyan, pelu irele. Amin
BIBELI KIKA: Johannu 8:31-47

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *