For Why Will You Die?

THE SEED

“Cast away from you all your transgressions, whereby ye have transgressed; and make you a new heart and a new spirit: for why will ye die, o house of Israel.” Ezekiel 18: 31

This message comes as a warning and encouragement for all people that goes to church but they are not truly born again and those that still wallow in sin. Why will you decide to die and go to hell fire when God has sent His only begotten Son ‘Lord Jesus’, the Saviour of the world to die on the cross of Calvary for our transgressions so that we can have life and have it in abundance. Why are we so stubborn to receive the free gift of righteousness through Christ Jesus and free from the bondage of sin. O sinners, Jesus is knocking at the door of your heart today. Do not procrastinate for tomorrow may be too late. It is better you accept the Lordship of Jesus Christ, repent genuinely in your heart, confess those iniquities, desist from them so the Holy Spirit can visit you and take charge of your entire life, because “it is a great thing when a wicked turneth away from his wickedness that he hath committed and doeth that which is lawful and right, then he shall save his soul alive.” Jesus promised us a place in His Father’s house which after we close our eyes from here we will not be a wanderer and perish but we’ll be with Him for eternity. Choose righteousness and life, say NO to hell fire where there is gnashing of teeth, sorrow, and everlasting condemnation.

PRAYER
Oh my Father I come before your throne of grace today, have mercy on me and forgive me all my transgressions so I can be an heir of your Kingdom through Jesus Christ. Amen.
BIBLE READINGS: Ezekiel 18:1-32

E E SE TI IWO YIO FI KU?

IRUGBIN NAA
“E ta gbogbo irekoja yin nu kuro lodo yin, nipa eyiti eyin fi rekoja, e si da okan titun ati emi titun fun ara yin. Nitori kini eyin o se ku, ile Isreali?” Ezekieli 18:31

Oro yii wa gege bii ikilo ati oro iyanju fun gbogbo awon ti nlo ile ijosin sugbon ti won kii se atunbi ati awon ti nwon si n pafo ninu ese. Eese ti iwo yio fi pinnu lati ku, ki o si lo si orun apaadi leyin ti Olorun ti ran Omo bibi re kan soso tiise Jesu Kristi, Olugbala araye lati ku ni ori igi agbelebu fun ese wa ki a baa le ri iye, ani ni kikun. Kilode ti a ko fe gba ebun ofe ti ododo nipa Kristi Jesu ki a si bo ninu ide ese. Elese, Jesu n kan ilekun okan re loni, mase fi igbala re dola nitori ola le peju. O dara ki o gba Jesu Kristi l’Oluwa, ronupiwada nitooto ninu okan re, jewo awon esee ni, jawo kuro ninu re ki Emi MImo baa le wonu okan re ki o si gba gbogbo isakoso aye re, nitori “nigbati eniyan buburu ba yipada kuro ninu iwa buburu re, ti o si se eyiti o to ti o si ye, on o ti ipa re wa laaye”. Jesu se ileri lati pese aye fun wa ni ile baba re, pe nigba ti a ba di oju wa si aye yii, aki yio je alarinkiri ki a si segbe sugbon a o wa pelu re titi ayeraye. Yan ododo ati iye, mase rin si ipa ona orun apaadi nibiti ekun, ipayinkeke ati iparun ayeraye wa.

ADURA
Baba mi, mo wa si iwaju ite oreofe re loni, saanu fun mi ki o si dari gbogbo aisedede mi ji mi, ki nba le je ajogun ijoba re nipase Jesu Kristi. Amin.
BIBELI KIKA: Ezekiel 18:1-32

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *