A Strong Tower

A STRONG TOWER

THE SEED
“The name of the LORD is a strong tower: the righteous runneth into it, and is safe.” Proverbs 18:10

The name of the LORD is a strong tower. The name of the Lord is where the strength lies. His name has all power to combat anything the enemy tries to raise against us. The name of the Lord is a name above every name. It is a refuge for us to run into and be safe from all the attacks that come against us. The name of the Lord is our divine protection, and we always need Him. The name of the Lord is strong against storms that would try to uproot us. The name of the Lord is secure. We are protected from harm and harassment of the enemy. The name of the Lord contains what we need in times of stress and anxiety if we will be quick to run to Him. Today we can speak His name over the circumstances that cause us to panic. Jesus is Lord over all sickness and disease. Dearly beloved, as believers, getting to His protection should be primary on our mind that we would run to the Lord rather than walk as if we had all day. Jump inside the strong tower of His name and lock the doors where nothing can get to you. Stand on the promises He gives and do not hesitate to believe it. Focus on His name and the meaning behind that name so powerful that every knee shall bow and tongue confess that Jesus Christ is Lord.

PRAYER
Lord Jesus continue to be my strong tower of refuge in Jesus name. Amen.

BIBLE READINGS: Exodus 3: 12-15; Acts 4: 1-12

ILE IṢỌ AGBARA

IRÚGBÌN NÁÀ
“Orukọ Oluwa ni ile-iṣọ agbara: awọn olododo sá wọ inu rẹ̀, o si wà lailewu” Owe 18:10

Orukọ Oluwa ni ile-iṣọ agbara. Orukọ Oluwa ni ibiti agbara gbe wa. Oruko Oluwa ni gbogbo agbára lati d’ojukọ ohunkohun ti ọta ngbiyanju lati fi ba wa ja. Orukọ Oluwa li orúkọ ti o ga ju gbogbo orukọ lọ́ . Orukọ Oluwa ni, idabobo atọ̀runwa, ti a si maa nilo rẹ nigba gbogbo. Oruko Oluwa lagbara lodi si awon iji ti o gbiyanju lati fà wa tu. Oruko Oluwa wa ni aabo. A ni aabo kuro lọwọ ibi ati ihalẹ̀ ọta. Orukọ Oluwa ni ohun ti a nilo ni akoko wahala ati aniyan, ti a ba yara sa lọ sọdọ Rẹ. Loni iwọ le pe orukọ rẹ lori awọn ipo ti ọ mu wa ni ijaaya. Jesu ni Oluwa lori gbogbo aisan ati arun. Olufẹ ọwọn, bi awọn onigbagbọ ti o sunmọ aabo rẹ; o yẹ ki o jẹ akọkọ ni ọkan rẹ pe o ni lati sare lọ si ọdọ Oluwa, jù ki maa ṣe iṣe bi enipe a ni gbogbo ọjọ. Lọ sinu ile- iṣọ orúkọ Rẹ ti o lagbara, ki o ti ilẹkun nibiti ohunkohun ko le de ọdọ rẹ. Duro lori awọn ileri ti o fun ọ, ati ki o ma ṣe ṣiyemeji lati gbagbọ. Kọ ojú mọ orukọ rẹ, ati awọn ìtumọ ti orukọ Rẹ ni, ti o lagbara, ti gbogbo eekun yoo wolẹ fun ati ahọn yíó jẹwọ pe Jesu Kristi ni Oluwa.

ADURA
Jesu Oluwa máa tẹsiwaju lati jẹ ile-iṣọ ti o lagbara fun mi ni orukọ Jesu Amin.

BIBELI KIKA: Eksodu 3: 12-15; Ise Awon Aposteli 4: 1-12

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *