REST IN ALL AREA

THE SEED

“But now the Lord my God has given me rest on every side, and there is no adversary or disaster.” 1 Kings 5:4 NIV

When you have a defined relationship with God, He will surely give you rest in all your ways just like King Solomon. God gave him rest in all his surroundings, he fought no battles because God won all his battles for him. God already promised to give everyone who comes to him rest by carrying their burden. God gives rest to His beloved, he blesses them in all ways just like our Father Abraham, He perfected everything concerning him. God is also ready to do the same and more for us to enjoy rest in our studies, job, business, family, children, ministry, etc. We should just keep following Him and obey His commandments, He told us to come to Him with our burdens, everything bothering us and lay it at the cross of Calvary and He promised to give us rest in all our ways and perfect everything concerning us. He can give us rest just like He gave King Solomon and even more when we keep trusting Him and obeying Him. He knows what we are going through and that this world is full of turmoil and pain, but He will be our peaceful and safe abode.

BIBLE READING: 1 King 5:2-4

PRAYER: Oh Lord, please give me rest in all my ways and perfect everything concerning me, Amen.

 

 

 ISIMI NÍ ÌHÀ GBOGBO

IRUGBIN NAA

“Ṣùgbọ́n nísinsìnyí Oluwa Ọlọ́run mí ti fun mi ni isinmi ni iha gbogbo, bẹni ko si ọ̀tá tàbí ibikan ti o ṣẹ”. Ọba kíni 5:4.

Nígbà tí o bá ní àjọṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run, dájúdájú yóò fún ọ ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà rẹ, gẹ́gẹ́ bí Ọba Sólómọ́nì. Ọlọ́run ti fún un ní ìsinmi ní gbogbo àyíká rẹ̀, kò ja ogun kankan nítorí pé Ọlọ́run ṣẹ́gun gbogbo ogun rẹ̀ fún un. Ọlọ́run ti ṣèlérí láti fún gbogbo ènìyàn. ẹniti o tọ̀ ọ wá ni isimi nipa rirù ẹrù wọn. Ọlọrun fi isimi fun awọn ayanfẹ rẹ̀, o nbukún wọn nigbagbogbo gẹgẹ bi baba wa Abrahamu, o mu ohun gbogbo di pipé nitori rẹ̀. Ọlọ́run tun ṣetan lati ṣé bakanna ati siwaju sii fun wa lati gbadun isinmi ninu Ẹkọ wa, iṣẹ, iṣowo, awọn ọmọ, idile, iṣẹ-iranṣẹ ati bẹbẹ lọ. Ki a maa tẹle ki a si pa awọn ofin Rẹ mọ, Ó sọ fun wa lati wa si ọdọ Rẹ pẹlu ẹrù wa, pẹ̀lú ohun gbogbo ti o n da wa lọ́kàn rú, ki a gbe e le Agbelebu Kalfari O si ṣé ileri lati fun wa ni isimi ni gbogbo ọ̀nà wa, ki o si ṣé ohun gbogbo nípa tí wa ní àṣepe. O le fun wa ni isimi gẹ́gẹ́ bi o ti fun Solomoni Ọba ati paapaa nigba ti a ba gbẹ́kẹ̀le e ti a si ṣègbọràn si ofin Rẹ. Ó mọ ohun tí a ń là kọjá àti bí ayé yìí ti kún fún ìdàrúdàpọ̀ àti ìrora ṣùgbọ́n yóò jẹ́ ibùgbé àlàáfíà àti ìgbàlà fún wa.

BIBELI KIKA: 1 Ọba 5:2-4.

ADURA: Olúwa, jọ̀wọ́ fún mi ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà mi, kí o sì, ṣé àṣepe ohun gbogbo nípa mi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *