PRAISING GOD IS THE REALTHING THE SEED

PRAISING GOD IS THE REAL THING

THE SEED
“O come, let us sing unto the LORD: Let us make a joyful noise to the rock of our salvation. Let us come before his presence with thanksgiving, And make a joyful noise unto him with psalms.” Psalm 95:1-2 KJV

It’s the second day of a new year—still praising God? Yes! Praise is always in season. Whether in a new or old year, God remains worthy. Today’s seed calls us to praise as individuals, families, and communities. You can be the one to initiate praise in your home, workplace, or church. Praise invites God into your year, and it aligns your heart with His will. Because we are the people of His pasture and the sheep of His hand, our worship brings down blessings and establishes God’s presence in our midst.

BIBLE READINGS: Psalm 95:1–7 (KJV)
PRAYER: Lord, teach me by Your Holy Spirit to champion Your praise among people. Amen.

YÍN YIN ỌLỌ́RUN NI O ṢEPÀTÀKÌ

IRUGBIN NAA
“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a kọrin sí OLUWA: Ẹ jẹ́ kí a hó ihò ayọ ̀ sí àpáta ìgbàlà wa.Ẹ jẹ́ kí a wá sí iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ ́, kí a sì fi orin mímọ́ hó ìho ayọ̀ sí ọ̀dọ̀ Rẹ̀.” Sáàmù 95:1-2

Ni ojo keji odun, Ṣé a si n tẹ síwájú láti yin Ọlọrun logo? Bẹẹni! Iyin maa n wa nigbagbogbo fun wọn akoko. Boya nínú ọdún titun tabi ọdún tó ti kọjá lọ, Ọlọrun wa ni yíyẹ. Irugbin ti oni n pe wa lati yin in bi awa eniyan, bi idile, bi agbègbè. O le jẹ ẹni ti o bẹrẹ iyìn ni ile rẹ, ní ibi iṣẹ rẹ, tabi ile ijọsin rẹ. Iyin a máa pe Ọlọrun sinu ọdun rẹ, yió si mu ọkan rẹ wa ni irẹpọ pẹlu ifẹ Rẹ̀. Nítorí pé àwa jẹ́ ènìyàn Rẹ̀ àti àwọn àgùntàn pápá Rẹ̀, ìyin wa maa ń sọ àwọn ìbùkún Rẹ̀ kalẹ̀, ó sì nfi ìdí íwà láàyè Ọlọ́run múlẹ̀ ní àárín wa.

BIBELI KIKA: Sáàmù 95:1-7 (KJV)
ADURA: Oluwa, kọ mi pẹ̀lú Ẹ̀mí Mímọ́ Rẹ lati gbe iyin Rẹ̀ ga larin àwọn eniyan. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *