GOD WILL MAKE AWAY
THE SEED
“The Lord shall fight for you, and you shall
hold your peace.” — Exodus 14:14 NKJV
The Israelites were trapped between the Red Sea and Pharaoh’s army, but God provided a way of escape. In moments of fear, uncertainty, and overwhelming pressure, God remains our refuge and strength. Rather than giving in to panic, let your heart rest in His promises. His presence will calm your fears and make a way where there seems to be none. Every Red Sea situation is an opportunity for God to show His power.
BIBLE READINGS: Exodus 14:10–31
PRAYER: Lord, help me to trust You completely and rest in Your power to deliver me. Amen.
ỌLỌ́RUN YÍÒ LA Ọ̀NÀ
IRUGBIN NAA
“Nítorí tí Olúwa yió ja fún yin, ki ẹ̀yìn kí ó sì pa enu yin mọ́ ” Ẹ́ KÍSÓDÙ 14:14.
Àwọn ọmọ Ísírẹlì há si àárín Òkun Pupa àti awon ọmọ oguń Fáráò, ṣùgbọ́ n Ọlọ́ run pèsè ọ̀nà àbáyọ. Ní àkókò ìbẹ̀rù, àìdánilójú, àti ìdààmú ńlá, Ọlọrun jẹ ibi ìsádi àti agbára wa. Dipo ki o so iréti nu ńitori ẹ̀rù, jẹ ki ọkan rẹ sinmi ninu awọn ileri Rẹ. Ìwàláàyè Rẹ, yio fí ọkàn ẹ̀rù rẹ balẹ, yio si ṣe ọna nibiti ọnà ko si. Gbogb̀ o Ok̀ un Pupa jẹ àǹfààǹ í Ọlọrun lati fi agbara Rẹ han.
BIBELI KIKA: Ẹ́ kísódù 14:10–31
ADURA: Oluwa, ran mi lowo lati gbẹ́kẹ̀le Ọ patapata, ki èmi kí ó le sinmi le agbara Rẹ lati gba mi. Amin.