TRUST THE UNFAILING GOD
THE SEED
“But blessed is the one who trusts in the Lord, whose confidence is in him.” — Jeremiah 17:7 NIV
Growing up, many of us held tightly to promises that were never fulfilled, leaving behind disappointment and mistrust. But unlike man, God’s promises are sure and unfailing. People may fail like Joseph’s brothers or Ananias and Sapphira did, but God never breaks His word. He is our Wonderful Counselor, Mighty God, and Everlasting Father (Isaiah 9:6). Trusting in Him is the only way to find peace and security. His promises are dependable, and He alone has the power to bring them to pass.
BIBLE READINGS: Isaiah 26:3–4
PRAYER: Thank You, Lord, for Your promises concerning my life. Help me to keep trusting You always. Amen.
G B Ẹ́ K Ẹ̀ L É Ọ L Ọ́ R U N T Í K Í I K Ù N À
IRUGBIN NAA
“Ibukun ní fún ẹnití ó gbẹ́kẹ̀le Olúwa tí ó si fi Olúwa ṣé ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀” Jeremiah 17:7.
Nigbati a ndagba, ọpọlọpọ wa ni o di awọn ìléríkanmutiwonkosiwasiimuse,eyitio si fa ìjàkulẹ àti àìegbẹ́kẹ̀lé. Ṣugbọn yàtọ̀ si ènìyàn, ìlérí Ọlọ́run dájú kó sí ní Ìkùnà. Awọn eniyan le kuna bi awọn arakunrin Josefu tabi Anania ati Safira ti ṣe, ṣugbọn Ọlọrun ko ni yẹ ọrọ Rẹ rara. Oun ni Iyanu Oludamọran, Ọlọrun Alagbara, ati Baba Ayérayé (Isaiah 9:6). Nini igbẹkẹle nínú Rẹ ni ọna kan ṣoṣo lati ni alaafia ati aabo. Awọn ileri Rẹ ṣé e gbẹkẹle, ati pe Oun nikan ni o ni agbara lati mu wọn ṣẹ.
BIBELI KIKA: Isaiah 26:3–4
ADURA: Mo dupẹ, Oluwa, fun awọn ileri Rẹ lori ayé mi. Ràn mi lọ́wọ́ lati ma gbẹ́kẹ̀le Ọ nigbagbogbo. Amin.