WELCOMING DIVINE MESSENGERS

THE SEED

“The Lord appeared to Abraham near the great trees of Mamre while he was sitting at the entrance to his tent in the heat of the day.” — Genesis 18:1 NIV

Abraham recognized and received divine visitors, and his hospitality opened the door for blessing. God often sends His help or direction through divine messengers—sometimes in unexpected forms. Divine encounters often come in ordinary moments. A heart that is sensitive to the Holy Spirit can discern God’s presence even in simple acts of kindness or unexpected visits. When we honour God’s messengers, we position ourselves to receive answers, direction, and blessings that may shape our destiny. A discerning heart and a spirit of hospitality allow us to align with God’s timing and receive His promises.

BIBLE READINGS: Hebrews 13:1–3

PRAYER: Lord, open my eyes to lovingly receive and honour Your messengers. Amen.

GBIGBAAWON IRANSE LALEJO

IRUGBIN NAA

Olúwa sì farahan Abrahamu nítòsí àwọn igi ńlá Mamre, bí ó ti jókòó ní ẹnu-ọ̀nà àgọ́ rẹ̀, nígbà tí ọjọ́-kanrí tí oòrùn sì mú. Genesisi 18:1

Abraham dá awon iranse mo, o gba won lalejo; eyi si si ilekun ibukun fún un. Olorun maa n saba ran iranlowo tabi itona Re lati owo awon iranse Re; ni igba miran lona airotele. Ìrinako ti emi saba maa n waye lairotele. Okan ti o ba si sile si Emi Mimo yoo mo igba ti Olorun ba wa ni tosi paapaa julo nipa awon aanu kekeeke tabi alejo ojiji. Ti a ba b’owo fun awon iranse Olórun, a n fi ara wa si ipo lati gba esi, itona, ati ibukun ti yio yi ayanmo wa pada. Okan ti o ni imo àti emi igbanilalejo yoo mu wa wa ni ibamu pelu akoko Olorun ati ileri Re

BIBELI KIKA: Heberu 13:1-3
ADURA: Oluwa, si mi ni oju lati le f’ife gba ati lati b’owo fún awon iranse Re. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *