YOU ARE NOT ALONE

THE SEED
“Fear not, for I am with you; be not dismayed, for I am your God. I will strengthen you, Yes, I will help you, I will uphold you with My righteous right hand.” – Isaiah 41:10 (NKJV)
Loneliness, fear, and discouragement can make anyone feel abandoned. But as a child of God, you are never alone. His presence is not seasonal; it is constant. Even when you don’t feel it, He is there. God’s promise to be with us is one of the most repeated assurances in Scripture. He was with Joseph in the pit and prison, Daniel in the lions’ den, and the three Hebrews in the fire. When God is with you, no situation can consume you. You are carried, covered, and sustained by His righteous hand.
BIBLE READINGS: Isaiah 43:1–7 (KJV)
PRAYER: Lord, thank You for Your constant presence. Help me to trust that I am never alone, no matter what I face. Amen.

O KÒ DÁNÌKAN WÀ
IRUGBIN NAA
Iwọ má bẹ̀ru; nitori mo wà pẹlu rẹ; má foyà; nitori emi ni Ọlọrun rẹ: emi o fun ọ ni okun; nitõtọ, emi o ràn ọ lọwọ; nitõtọ, emi o fi ọwọ́ ọ̀tun ododo mi gbe ọ sokè. Isaiah 41:10
Idawa, eru àti ijakule le mu ki o dabi wipe a ko eniyan sile. Sugbon Gege bí omo Olorun, o kò nikan wa. Iwalaaye Re kii se fun igba kan, o duro lai. Bi iwo kò tile gburo re, sibe, O wa nibe. Ileri Olorun lati wa pelu wa je okan ninu awon idaniloju inu Iwe mimo ti Olórun se fún wa. O wa pelu Josefu ninu ihò ati ninu ewon, Danieli ninu iho kiniun àti awon Heberu meta ninu ina. Ti Olórun ba wapelurekosiipokantiolegbeomi.Oti dienitiagbé,tiabò,tiododoOlorungbéró.
BIBELI KIKA: Isaiah 43:1-7
ADURA: Oluwa, mo dupe fun iwalaaye Re laye mi. Ran mi lowo lati gbagbo wipe mi o da wa ni abe botiwukori. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *