THE SEED
“For we are his workmanship, created in Christ Jesus unto good works, which God hath before ordained that we should walk in them.” – Ephesians 2:10 (KJV)
God created every believer with a divine assignment in mind. Once we are saved, His purpose begins to unfold step by step. These good works were prepared long before we were born, and walking in them brings fulfillment and glory to God. Wherever you find yourself—home, church, or workplace—there is a role for you to play in God’s plan. Don’t live idly. Be intentional about adding value and letting your light shine. God rewards faithfulness in every area where He has called you to serve.
BIBLE READINGS: Matthew 25:14–23 (KJV)
PRAYER: Father, reveal to me the good works You have prepared for me. Give me grace to walk in them faithfully and diligently, in Jesus’ name. Amen.
GBARADI FUN ISE RERE
IRUGBIN NAA
Nitori awa ni iṣẹ ọwọ́ rẹ̀ ti a ti dá ninu Kristi Jesu fun iṣẹ rere, ti Ọlọrun ti pèse tẹlẹ, ki awa ki o le mã rìn ninu wọn. Efesu 2:10
Olorun da gbogbo onigbagbo pelu ise iranse atorunwa lokan. Bi a ba ti ri igbala, eto re a bere sii Farahan leseese. Awon ise rere wonyi ni ati pese sile ki won to biwa, o si mu imuse ati ogo fun Olorun nigba ti a ba nrin ninu won.nibikibi ti o ba ti ba ara re, boya ile ni, tabi ninu ijo tabi ibi ise , ise wa fun o lati se ninu eto Olorun. Ma se imele. Je eni ti o ni iwulo, ki o si jeki imole re tan. Olorun ma npin ere fun isotito ni gbogbo ona ti o ti pe o lati sise.
BIBELI KIKA: Matteu 25:14-23
ADURA: Baba fi han mi, gbogbo ise rere ti o ti pese sile fun mi. fun mi ni ore ofe lati rin ninu won lotito ati pelu itara ni oruko Jesu. Amin.