THE SEED
“Let us hold fast the profession of our faith without wavering; (for he is faithful that promised;)” – Hebrews 10:23 (KJV)
Life’s storms can shake even the strongest person, but hope anchors us to God’s faithfulness. Faith believes, love strengthens, but hope keeps us looking up, trusting in God’s promises. Our Father has good plans for us — plans to give us a future and a hope. When the night seems long, remember that joy comes in the morning. He is faithful to bring you through and never leaves His children stranded.
BIBLE READINGS: Romans 5:1–5 (KJV)
PRAYER: Father, God of all hope, fill me with faith, love, and hope to stand firm in every situation. Amen.
OLORUN GBOGBO IRETI
IRUGBIN NAA
Ẹ jẹ ki a dì ijẹwọ ireti wa mu ṣinṣin li aiṣiyemeji; (nitoripe olõtọ li ẹniti o ṣe ileri. Heberu 10:23
Igbi aye le mi eni to lagbara ju, sugbon ireti lo so wa ro mo otito Olorun. Igbagbo nsise igbagbo, ife nfun ni ni okun, sugbon ireti lo nmu wa gbojusoke lati gbekele ileri Oluwa. Baba wa ni eto rere fun wa, eto lati fun wa ni ojo iwaju ati ireti. Nigbati ale ba pe, ranti wipe ayo nbo lowuro. O se olododo lati mu wa bori, ko si ni fi awon omo re sile laini iranwo.
BIBELI KIKA: Romu 5:1-5
ADURA: Baba, Olorun gbogbo ireti, kun mi pelu igbagbo, ife ati ireti lati duro sinsin ninu gbogbo ipo. Amin.