BE YOURSELF

THE SEED

“But Daniel purposed in his heart that he would not defile himself with the portion of the king’s meat, nor with the wine which he drank.” – Daniel 1:8 (KJV)

To be yourself in Christ is to stand firm in your faith regardless of pressure. Daniel refused to compromise even when everyone around him followed the king’s command. Many voices will try to shape your identity, but God calls you to be true to who He created you to be. Be bold in your convictions, and let your faith be unwavering. Your authenticity in Christ can inspire others to stand firm.

BIBLE READINGS:  Romans 12:1–2 (KJV)

PRAYER: Father, help me to stand firm in You and remain true to who You created me to be. Amen.

JE ARA RE

IRUGBIN NAA

Ṣugbọn Danieli pinnu rẹ̀ li ọkàn rẹ̀ pe, on kì yio fi onjẹ adidùn ọba, ati ọti-waini ti o nmu ba ara on jẹ: nitorina o bẹ̀ olori awọn iwẹfa pe, ki on má ba ba ara on jẹ. Daniel 1:8

Lati je ara re ninu Kristi oun ni wipe ki o duro sinsin ninu igbagbo re bi atako tile po. Danieli ko lati darapo mo aye nigba ti gbogbo awon ti won yiika tele ase oba. Opolopo ohun ni yio ma gbiyanju lati mo ayanmo re, sugbon Olorun pe o lati se otito si eni ti o da o lati je. Ni igboya ninu igbagbo re, ma si se jeki igbagbo re ye. Otito re ninu Kristi le ko awon miran lati duro sinsin.

BIBELI KIKA: Romu 12:1-2

ADURA: Baba, ranmi lowo lati duro sinsin ninu re ki n si je olotito si eni ti o dami lati je. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *