YOU ARE CHOSEN AND PECULIAR!

THE SEED

“But ye are a chosen generation, a royal priesthood, an holy nation, a peculiar people that ye should shew forth the praises of him who hath called you out of darkness into his marvellous light.” – 1 Peter 2:9

God has set you apart as a chosen generation, designed for greatness. You are not meant to live defeated or insignificant lives but to operate in dominion and authority. Challenges and trials are part of the enemy’s attempts to discourage you, but they cannot change your identity in Christ. Recognizing that you are chosen allows you to respond to trials with faith and courage, standing firm as a child of God. Like a prince, you confront challenges from a position of authority. God has called you out of darkness into His marvelous light, and nothing can nullify His purpose for your life.

BIBLE READINGS:  Ephesians 1:3–10 (KJV)

PRAYER: Lord, help me to always remember that I am chosen and beloved, and empower me to live in the authority You have given me, in Jesus’ name. Amen.

 

AYANFE ATI ENIYAN OTO NI O

IRUGBIN NAA

Ṣugbọn ẹnyin ni iran ti a yàn, olu-alufa, orilẹ-ède mimọ́, enia ọ̀tọ; ki ẹnyin ki o le fi ọla nla ẹniti o pè nyin jade kuro ninu òkunkun sinu imọlẹ iyanu rẹ̀ hàn: I Peteru 2:9

 

Olorun ti ya o soto gege bi iran ti a yan, ti a se loso fun igbega. A ko da o lati gbe igbe aye bi ẹniti ti ogun bori re tabi aye ti ko ni itumo, bikose  lati se akoso, ki o si je alase. Ipenija ati idanwo ni ara awon ohun ti ota maa fi nmu o rewesi, sugbon won ko le yii idanimo re ninu Kristi pada. Nigbati o ba mo wipe o je ẹniti a yan, eyi yio mu ki o fi igbagbo ati igboya koju idanwo, Iwo yio si duro gangan, gege bi omo Olorun. Gege bi omo oba, iwo yio koju ipenija lati ipo ase. Olorun ti pe o kuro ninu okunkun, sinu imole iyanu re, kosi si ohun ti o le ba eto Re fun aye re je.

 

BIBELI KIKA: Efesu 1:3-10

ADURA: Oluwa, ranmilowo lati maa ranti nigba gbogbo wipe, mo je eniti a yan, ti a fe, funmi lagbara lati maa gbe ninu ase ti o ti fifun mi, ni Oruko Jesu, Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *