GOD WHO PARDONS

THE SEED

“Who is a God like unto thee, that pardoneth iniquity, and passeth by the transgression of the remnant of His heritage? He retaineth not His anger for ever, because He delighteth in mercy.” – Micah 7:18 (KJV)

Prophet Micah was in awe of the mercy and grace of God. Despite the sins of His people, God had already made a way for reconciliation through Jesus Christ. Unlike the devil who encourages sin, God pardons and restores. There are no “big” or “small” sins in the eyes of God; all sin separates us from Him. But through genuine repentance and faith in Christ, forgiveness is freely given. God does not delight in punishing His children but in showing mercy. All He requires is that we confess, repent, and turn away from sin.

 

BIBLE READINGS:  Micah 7:18–20 (KJV)

PRAYER: Lord, have mercy on me. Cleanse me from all iniquities and restore me by Your mercy, in Jesus’ name. Amen.

 

OLORUN OLUDARIJI

IRUGBIN NAA

Tani Ọlọrun bi iwọ, ti o ndari aiṣedede jì, ti o nre iyokù ini rẹ̀ kọja? kò dá ibinu rẹ̀ duro titi lai, nitori on ni inudidun si ãnu. MIKA 7:18

 

Aanu ati ore-ofe Olorun ya Woli Mika lenu pupo. Pelu gbogbo ese awon eniyan re, Olorun ti pese aye fun ibalaja nipase Jesu Kristi. Nigbati esu nmuni dese, Olorun ndariji, o si n dawapada si ipo. Ko si ese ti o tobi tabi ti o kere ni oju Olorun, gbogbo ese ni nya wa nipa kuro lodo Re. Sugbon nipase ironupiwada tooto ati igbagbo ninu Kristi, a ri idariji gba lofe. Olorun ko ni inu didun ninu fifi iya je awon omo Re sugbon O fe lati fi aanu han fun won. Kiki ohun ti O fe nipe ki a jewo ese wa, ki a ronupiwada, ki a si yipada kuro ninu ese.

 

BIBELI KIKA: Mika 7:18-20

ADURA: Oluwa, saanu fun mi, we mi nu kuro ninu gbogbo aisedede mi, ki o si da mi pada si ipo nipa aanu Re ni oruko Jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *