GOD’S WAY, GOD’S STANDARD

THE SEED

“For they being ignorant of God’s righteousness, and going about to establish their own righteousness, have not submitted themselves unto the righteousness of God.” – Romans 10:3 (KJV)

Many try to set up their own way to be right with God, but God has only one way—Jesus Christ. His standard is righteousness, and there’s no alternative. Self-righteousness or excuses like “God understands” cannot meet God’s standard. Jesus came to show us the way and to empower us to live a righteous life. His blood remains the only means by which we are reconciled to God. Submitting to God’s way is the only path to life; any other path leads to destruction.

BIBLE READINGS:  Romans 10:1–10 (KJV)

PRAYER: Lord Jesus, help me to embrace Your way and Your standard wholeheartedly, and not be deceived by my own reasoning. Amen.

 

ONA OLORUN, OFIN OLORUN

IRUGBIN NAA

Nitori bi nwọn kò ti mọ ododo Ọlọrun, ti nwọn si nwá ọna lati gbé ododo ara wọn kalẹ, nwọn kò tẹriba fun ododo Ọlọrun. Romu 10:3

Opolopo eniyan lo ngbiyanju lati mu ona won pe niwaju Olorun, sugbon ona kan soso ni Olorun ni, eyi ti nse Jesu Kristi. Ododo ni ofin Re, kosi si ona miran. Ododo ara-eni tabi awon awawi bii “O ye Olorun” ko le ba ofin Olorun mu. Jesu wa lati fi ona han wa, ati lati fun wa lagbara lati gbe igbe aye ododo. Eje Re nikan ni a fi rawa pada sodo Olorun. Ki a jowo aye wa lati rin ni ona Olorun nikan ni ona si iye. ona imoran, iparun ni.

 

BIBELI KIKA: Romu 10:10

ADURA: Jesu Oluwa, ranmilowo lati le gba ona Re ati ofin Re tokantokan, ki iro inu mi mase tan mi je. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *