THE SEED
“Brethren, my heart’s desire and prayer to God for Israel is, that they might be saved.” – Romans 10:1 (KJV)
Every believer carries a divine mandate to care for the lost. Apostle Paul’s heartfelt prayer for the salvation of his people reveals the burden we must have for souls. A true child of God does not live for themselves alone—they live to bring others to Christ. Evangelism begins with compassion, prayer, and a lifestyle that reflects Christ. You may not carry a Bible everywhere, but your life should speak louder than words. When people see Jesus in your words, conduct, and love, they are drawn to Him.
BIBLE READINGS: Matthew 9:35–38 (KJV)
PRAYER: Lord, ignite in me the fire of compassion to win souls to Your kingdom. Use me as a vessel to bring others to You. Amen.
AANU FUN AWON OKAN
IRUGBIN NAA
ARÁ, ifẹ ọkàn mi ati adura mi si Ọlọrun fun Israeli ni, fun igbala wọn. Romu 10:1
Gbogbo onigbagbo ni a fi ran lati maa se itoju awon ti o sonu. Adura ti Paulu Aposteli fi tokantokan gba fun igbala awon eniyan Re fihan iru ajaga ti a gbodo ru nitori awon okan naa. Omo Olorun tooto kii gbe ninu aye nitori ti ara won nikan. Nwon wa laye ki won le mu awon eniyan wa sodo Kristi. Ise ihinrere bere pelu aanu, adura ati igbe aye to fi Kristi han. O ko ni lati maa gbe Bibeli kaakiri, sugbon igbe aye Re gbodo fohun ju oro lo. Nigbati awon eniyan ba ri Jesu ninu oro, ise, ife re, nwon yio sunmo Olorun.
BIBELI KIKA: Matteu 9:35-38
ADURA: Oluwa, da ina aanu sinu mi kin jere okan si ijoba Re. Lo mi gege bi ohun elo lati mu awon eniyan to o wa. Amin