THE SEED
“And if children, then heirs; heirs of God, and joint-heirs with Christ; if so be that we suffer with him, that we may be also glorified together.” – Romans 8:17 (KJV)
As God’s children, we are entitled to both earthly and heavenly blessings. On earth, God blesses those who diligently seek Him, just as He blessed Abraham, Isaac, Jacob, and others. But the ultimate inheritance is eternal—reigning with Christ in glory as joint heirs with Him.
This double blessing is a call to live faithfully, to lay hold of earthly assignments and to prepare for heavenly rewards. Do not let anything rob you of what belongs to you in Christ. Walk in your inheritance with faith, obedience, and perseverance.
BIBLE READINGS: Romans 8:14–21 (KJV)
PRAYER: Almighty Father, let no plan of the enemy rob me of my earthly and heavenly blessings. Strengthen me to walk in my inheritance in Christ. Amen.
ILERI IBUKUN NI ILOPO MEJI
IRUGBIN NAA
Bi awa ba si jẹ ọmọ, njẹ ajogun li awa, ajogun Ọlọrun, ati ajumọ-jogun pẹlu Kristi; biobaṣepe awa bá a jìya, ki a si le ṣe wa logo pẹlu rẹ̀. Romu 8:17
Gege bi omo Olorun, a ni eto si ibukun nile aye ati Ibukun lorun. Olorun maa n bukun gbogbo awon to fara bale wa A, gege bi O ti bukun fun Abrahamu, Isaaki, Jakobu, ati awon iyoku. Sugbon ogun wa ti o ga ju, ni ayeraye – ki a joba pelu Kristi ninu ogo gege bi ajumojogun pelu Re. Ibukun ilopo meji yii je ipe lati maa gbe igbe aye ododo, ki a dawole ise wa ti a ran wa laye, ki a si mura fun ere ti orun. Mase je ki ohunkohun o gba ohun ti nse tire ninu Kristi lowo re. Maa rin ninu ogun re pelu igbagbo, igboran ati suuru
BIBELI KIKA: Romu 8:14-21
ADURA: Baba alagbara, mase je ki imo ota gba ibukun mi ti aye ati Ibukun mi ti orun. Fun mi lagbara lati rin ninu ogun mi ninu Kristi. Amin