GOD IS GOOD ALWAYS

GOD IS GOOD ALWAYS

THE SEED

“For the Lord is good; his mercy is everlasting; and his truth endures to all generations.”  Psalm 100:5

Circumstances change; God’s character does not. His goodness is not the absence of hardship but the steadfast presence of a faithful God within it. He lavishes common grace sun and rain on all and covenant mercy on His people, generation after generation. Mercy that never ends and truth that never expires anchor our hearts when life feels unfair. The cross is the clearest proof: God gave His Son to give us life. If He did not spare Him, will He not also with Him graciously give us all things needed for His purposes? Imitate your Father: do good, show mercy, speak truth. In doing so, you mirror the nature of the One you worship. Let God’s unchanging goodness define your expectations more than your present season.

 

BIBLE READINGS:  Psalm 103:1–4

PRAYER: From everlasting to everlasting, I praise You for Your goodness and mercy. Amen.

 

OLUWA DÁRA NÍ GBOGBO ÌGBÀ̀

IRUGBIN NAA

Nítorí tí Olúwa pọ̀ ní oore, ìfẹ́ rẹ̀ sì wà títí láé; àti òtítọ́ rẹ̀ láti ìran de ìran. – Orin Dafidi 100:5

 

Ayida aye le yipada;iwa Olorun ki n yi pada. Ore re ko so wipe isoro ki yóò si, sugbon wipe Olorun olotito yóò wa ninu re. O n fun gbogbo eniyan ni ore ofe – òjò ati oòrùn si gbogbo eniyan – ati majemu aanu si awon tire lati iran de iran. Aanu ti kii  n tan pelu otito re ti kii  n ṣá mu okan wa duro nigba ti aye ba ku diekaato. Iku re lori igi agbelebu je eri to fihan julo: ani Olorun fi omo Re fun wa ki a baa le ni iye. Níwọ̀n ìgbà tí Ọlọ́run ti fi Ọmọ rẹ̀ fún wa, ǹjẹ́ ó ha tún le ṣòro fún un láti fún wa ní ohunkóhun fun ife Re bí? Fi iwa jo Baba re: se rere, fi aanu han, so otito. Ninu sise eleyi, oó dabi eni ti iwo n sin. Je ki didara Olorun ti ko yipada dari ireti re, má se wo ohun ti iwo n la koja ni akoko yii.

 

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 103: 1-4

ADURA: Lati ayeraye de ayeraye, mo yin o fun ore re ati aanu Re. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *