THE GOOD SHEPHERD
THE SEED
“I am the good shepherd. The good shepherd lays down his life for the sheep.” John 10:11
Jesus knows His own your wounds, worries, and wanderings and still calls you by name. As the Good Shepherd, He provides rest, restores souls, protects from wolves, and leads through dark valleys. His care is personal and His guidance is trustworthy. When the Lord is your Shepherd, provision and protection are not theories but testimonies. He redirects from dangerous paths, disciplines in love, and delivers from what devours. To follow Him is to learn His voice and prefer His path over every counterfeit pasture. Lack is not your portion when Christ is your Shepherd; His goodness and mercy pursue you all your days. Safety is found not in a place but in the presence of your Shepherd.
BIBLE READINGS: Ezekiel 34:11–16
PRAYER: Good Shepherd, lead, provide, and guard me. Let Your banner over me be love and peace. Amen.
OLÙṢỌ́-ÀGÙNTÀN RERE
IRUGBIN NAA
“Èmi ni olùṣọ́-àgùntàn rere: olùṣọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn. – Johanu 10:11
Jesu mọ awon tirẹ̀ – Ó mọ ọgbẹ́ re, aniyan re ati irinkerindo re – o si n pe o ni oruko. Gege bi Oluso-aguntan rere, o n pese isimi fun o, o tu okan re lara, o dabo bo ọ lowo ikoko, o si dari re ninu petele to sokunkun. Ìkẹ́ re wa fun o, itona re si ṣeé gbokan le.Nigbati Olorun ba je oluso-aguntan re, ipese ati abo yóò je eri re. Yóò dari re kuro ninu ona iparun, yóò ba o wi ni ife, yóò si gba o kuro lowo oun ti o le pa o lara. Lati tele e ni lati mo ohun re, ki a si fe ona Re ju awon ona miiran. O ko le s’alaini nigba ti Kristi ba je oluso-aguntan re. Ire ati aanu Re yo ma to o lehin ni gbogbo ojo re. Abo ko si ni ibikan bikose ni odo Oluso-aguntan re.
BIBELI KIKA: Ezekieli 34: 11-16
ADURA: Oluso-aguntan rere, dari mi, pese fun mi,ki o si so mi. Je ki ife ati alaafia Re je ọ̀págun lori mi. Amin.