PEACE THAT STANDS FIRM

PEACE THAT STANDS FIRM

THE SEED

“You will keep in perfect peace those whose minds are steadfast, because they trust in you.” — Isaiah 26:3 (NIV)

Perfect peace is not the absence of storms but the presence of God’s unshakable calm in the midst of them. The world offers fleeting calmness, but God offers a peace that anchors the soul. This peace keeps our hearts steady and ears open to God’s voice even when life’s pressures intensify. It builds unshakable faith that cannot be moved by fear. Trusting God completely is the key that unlocks this peace. A steadfast mind is one fixed on God, refusing to be tossed by the storms of life. Such a person enjoys God’s perfect peace.

Reflection: Trust in God creates a peace no storm can break.

 

BIBLE READING: Isaiah 26:1–4

PRAYER: Lord, help me to trust You with a steadfast heart and enjoy Your perfect peace always. Amen.

 

ÀLÀÁFÍÀ TÍ Ó DÚRÓ ṢINṢIN

IRUGBIN NAA:

“Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà pípé ọkàn ẹni tí ó dúró ṣinṣin, nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.” — Isaiah 26:3

Àlàáfíà pípé kì í ṣe àìsí ìjì, bikose iwalaaye itunnu Ọlọ́run nínú àárín wọn. Ayé lè fúnni ní ìfọ̀kànbalẹ̀ ìgbà díẹ̀, ṣùgbọ́n Ọlọ́run ni ó ń fúnni ní àlàáfíà ti o lè gbé ọkàn ró. Àlàáfíà yìí ń jẹ́ kí ọkàn wa dúró ṣinṣin, tí ó sì ń jẹ́ kí etí wa ṣí sí ohùn Ọlọ́run, bí ogun naa tilẹ̀ le. O n funni ni igbagbo ti iberu ko le bori. Igbekele ninu Olorun ni ó le mú irú àlàáfíà yii wa. Ọkàn tí ó dúró ṣinṣin ni ọkàn tí ó tẹjú mọ́ Ọlọ́run, tí kò sì jẹ́ kí ìjì ayé gbáa kiri

Àṣàrò: Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run ló ń mú àlàáfíà wá, tí ìjì kò sì lè fọ́.

 

BIBELI KIKA: Isaiah 26:1–4

ADURA: Oluwa, ràn mí lọ́wọ́ láti gbẹ́kẹ̀lé Ọ pẹ̀lú ọkàn didúró ṣinṣin. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *