BEYOND KNOWLEDGE—TO TRUE BELIEF

BEYOND KNOWLEDGE—TO TRUE BELIEF

THE SEED

“But there are some of you who do not believe.” For Jesus knew from the beginning who they were who did not believe, and who would betray Him.” — John 6:64 (NKJV)

Many followed Jesus during His ministry, but not all truly believed in Him. Some enjoyed His miracles without embracing His lordship. Knowing about Jesus is not the same as trusting and walking with Him fully. Even today, some profess faith outwardly but live with unbelief inwardly. True belief goes beyond hearing the Word it involves obeying and allowing it to transform our hearts and daily choices. Jesus calls us to rise to a higher level where we don’t just hear the truth but live it and reflect it in every part of our lives.

Reflection: Head knowledge doesn’t save true belief does.

 

BIBLE READING: John 6:60–69

PRAYER: Lord Jesus, help me to believe, live, and walk in Your truth daily. Amen.

 

O KỌJÁ ÌMỌ̀ — SÍ ÌGBÀGBỌ́ TÒÓTỌ́

IRUGBIN NAA:

“Ṣùgbọ́n àwọn kan wà nínú yín tí kò gbàgbọ́.” Nítorí Jesu mọ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ wá ẹni tí wọ́n jẹ́ tí kò gbàgbọ́, àti ẹni tí yóò fi òun hàn.” — Jòhánù 6:64

Ọ̀pọ̀ tẹ̀lé Jésù nígbà iṣẹ́-ìránṣẹ́ Rẹ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo wọn ni wọ́n gbà á gbọ́ ní tòótọ́. Díẹ̀ gbádùn iṣẹ́ ìyanu Rẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kò gba ipò Rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Oluwa. Mímọ̀ nípa Jésù kì í ṣe ohun kan náà pẹ̀lú gbígbẹ́kẹ̀lé e àti rírìn pẹ̀lú Rẹ̀. Lónìí náà, àwọn kan ń jẹ́wọ́ ìgbàgbọ́ pẹ̀lú ẹnu, ṣùgbọ́n wọ́n ń gbé pẹ̀lú aigbagbọ nínú ọkàn. Ìgbàgbọ́ tòótọ́ kọjá gbígbọ́ Ọ̀rọ̀ náà; ó jẹ́ ìgbọràn, ìyípadà ọkàn, àti ìṣe ojoojúmọ́. Jesu pe wa lati dide si ipele ti n gbo oro otito, ti sii n se afihan re ninu igbe aye wa.

ÀṢÀRÒ: Ìmọ̀ nìkan kì í tó; ìgbàgbọ́ tòótọ́ ni ó ń yi ayé padà.

 

BIBELI KIKA: Jòhánù 6:60–69

ADURA: Oluwa, ràn mí lọ́wọ́ láti gbàgbọ́, láti gbé, àti láti rin nínú òtítọ́ Rẹ. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *