STRENGTH FOR THE NEXT STEP
THE SEED
“Blessed are those whose strength is in you, whose hearts are set on pilgrimage.” — Psalm 84:5 (NIV)
Life sometimes winds through the Valley of Baca places of tears and unanswered questions. Yet the pilgrim whose heart is set on God discovers unexpected wells: grace sufficient for today and strength promised for tomorrow. You don’t need every answer to keep moving; you need the strength God gives. “They go from strength to strength, till each appears before God in Zion” (v.7). As you lean into His presence, He becomes your sun and shield, your present help and future hope. Look back and you’ll see His quiet footprints in your darkest stretches. Look ahead and you’ll find He is already there. Keep walking—He is not finished with your story.
Reflection: God gives today’s strength for today’s step.
BIBLE READING: Psalm 84:5–12
PRAYER: Lord, supply strength for today and hope for tomorrow as I walk with You. Amen.
IPA FUN IPELE TO KAN
IRUGBIN NAA:
Ibukún ni fun enia na, ipá ẹniti o wà ninu rẹ: li ọkàn ẹniti ọ̀na rẹ wà. ORIN DAFIDI 84:5
Nigba miran, aye a maa mu wa la afonifoji Baka- Ibi omije ati ibeere ti ko ni idahun. Sugbon awon atipo ti won fokan sodo Olorun maa nri orisun omi ti won ko ni ireti: oreofe ti o to fun ojo oni ati ileri ipa fun ojo ola. O ko nilo gbogbo idahun lati tesiwaju bikose ipa ti Olorun maa nfi funni. Won a maa ti ipa de ipa, titi olukuluku yio fi duro niwaju Olorun ni Sioni ( Ese 7) Bi o ti se nwa si iwaju Re, Yio di oorun ati asa re, lowolowo iranlowo ati ireti ojo ola re.
ERO: Olorun maa nfunni ni ipa ti o nilo fun igbese ti ojo oni.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 84:5-12
ADURA: Oluwa, fun mi ni okun fun ojo ti oni, ati ireti fun ojo ola, bi mo ti nba O rin. Amin