GRATITUDE THAT GROWS GRACE
THE SEED
“Be careful for nothing; but in every thing by prayer and supplication with thanksgiving let your requests be made known unto God.” — Philippians 4:6 (KJV)
A grateful heart sees God clearly in every season. David thanked God in triumph and in trouble, and that posture made him a “man after God’s own heart.” Gratitude isn’t denial of pain; it is declaration of God’s goodness over our pain.
Thanksgiving multiplies joy, steadies the soul, and keeps our prayers from becoming complaints. It opens new doors because it agrees with Heaven’s verdict: God is worthy—before, during, and after the answer. Choose gratitude daily—by praise, obedience, service, and witness. As you give thanks for what God has done and who He is, you’ll find that peace deepens and faith strengthens.
Reflection: Gratitude is faith made audible.
BIBLE READING: Psalm 136:1–10
PRAYER: Father, give me a thankful heart in every circumstance. Let gratitude overflow and keep me in Your peace. Amen.
EMI IMORE TI NMU OREOFE POSI
IRUGBIN NAA:
Ẹ máṣe aniyàn ohunkohun; ṣugbọn ninu ohun gbogbo, nipa adura ati ẹbẹ pẹlu idupẹ, ẹ mã fi ìbere nyin hàn fun Ọlọrun. FILIPI 4:6
Okan imore maa nri Olorun ni gbogbo asiko. Dafidi yin Olorun nigba ti o segun ati nigba isoro, eyi si mu ki o je “Eni bi okan Olorun” Imoore ko tumo si pe, ko si irora, o je sisoro nipa ore Olorun ju awon irora wa lo. Idupe maa nso ayo di pupo, o nmu okan ro, kii je ki adura wa dabi irahun. O maa n si ilekun titun nitori yio wa ni ibamu pelu ti orun. Olorun ye fun iyin – saaju, nigbati adura ba gba ati leyin igbati adura ba gba. Pinnu lati maa dupe lojoojumo- nipa iyin, igboran, ise isin ati eri re. Bi o ti ndupe fun ohun ti Olorun ti se ati nitori ohun ti O je, iwo yoo ri wipe alafia jinle, igbagbo si n funni lokun.
ERO: Emi imoore ni igbagbo tin fohun
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 136:1-10
ADURA: Baba, fun mi ni okan ope ninu ohun gbogbo. Je ki idupe mi kun akunwosile, ki o si pami mo ninu alafia Re. Amin