DON’T LISTEN TO THE CROWD

DON’T LISTEN TO THE CROWD

THE SEED

“And the multitude rebuked them, because they should hold their peace: but they cried the more, saying, Have mercy on us, O Lord, thou Son of David.” — Matthew 20:31 (KJV)

Two blind men cried out to Jesus for mercy, but the crowd tried to silence them. Refusing to be discouraged, they cried even louder—and Jesus stopped for them. Many times, the voices around us try to drown out our faith, but persistence breaks through barriers. Daniel also faced attempts to silence his prayer life. But he continued, and God shut the lions’ mouths. The same God responds today when we press in despite distractions and opposition. Whenever you’re told to be quiet, pray harder. When you’re mocked for your faith, stay focused on Jesus. Don’t let the crowd dictate your faith journey. God hears those who refuse to give up.

Reflection: The louder the resistance, the stronger your persistence must be.

BIBLE READING: Matthew 20:29–34

PRAYER: Lord, help me to keep my eyes fixed on You. Strengthen me to pray and believe even when others try to silence my faith. Amen.

 

MASE FETI SI OPO ENIYAN

IRUGBIN NAA:

Awọn enia si ba wọn wi, nitori ki nwọn ki o ba le pa ẹnu wọn mo: ṣugbọn nwọn kigbe jù bẹ̃ lọ, wipe, Oluwa, iwọ Ọmọ Dafidi, ṣãnu fun wa. Matteu 20:31

Awon afoju meji kigbe soke si Jesu fun aanu, awon eniyan dawon lekun, wipe ki won pa enu won mo. Sugbon won kigbe ju bee lo. Jesu si dese duro fun won. Lopo igba, awon ohun ti o yi wa ka maa fa igbagbo wa sehin, sugbon ti a ba teramo, a o mu idena kuro. Danieli paapaa ri idojuko nigbati won gbiyanju lati pa lenu mo nipa adura gbigba, sugbon o tesiwaju. Olorun si pa kiniun lenu mo. Olorun kanna lo n gbo adura loni nigbati a ba teramo adura laiwo ohun ti aye tabi atako. Nigbati won ba fe pa o lenu mo, tera mo adura, bi won ba ngan o nitori igbagbo re, koju si Jesu. Mase je ki awon eniyan se akoso irin ajo igbagbo re. Olorun maa ngbo ti awon ti ko dekun ati maa ke pe.

ERO: Bi o tile wu ki won maa da o lekun to, bee ni ki o tubo tera mo.

BIBELI KIKA: Matteu 20:29-34

ADURA: Oluwa, ranmi lowo lati gboju mi le O. Fun mi lagbara lati gbadura, ki nsi ni igbagbo nigbati awon eniyan ba tile nfe lati pa igbagbo mi lenu mo. Amin

 

 

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *