HOLDING FIRM TO THE END
THE SEED
“For we are all partners with Christ if we hold firmly to the end the confidence we had at the beginning.” — Hebrews 3:14 (GNB)
Motivation is a good starting point, but it is discipline that sustains faith. We will not always “feel” motivated to obey God or keep standing in faith, especially when our circumstances seem unchanged. That is where discipline takes over—choosing to stand on God’s promises even when emotions fade. Before any promise is fully manifested, there is often a silent period that tests our endurance. Many give up in this waiting season, but those who hold firm inherit the promise. Faith that endures is stronger than faith that starts with excitement. Let your walk with God be built on more than feelings. Let it be grounded in trust, obedience, and discipline to stand to the very end.
Reflection: Faith that endures will always outlast feelings.
BIBLE READING: Hebrews 3:12–15
PRAYER: Heavenly Father, give me strength and discipline to stand firm in faith until the very end. Amen.
DI I MU SINSIN TITI DE OPIN
IRUGBIN NAA:
“Nítorí àwa di alábápín pẹ̀lú Kristi, bí àwa bá di ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìgbẹ́kẹ̀lé wa mú ṣinṣin títí dé òpin;” – Heberu 3:14
Iwuri lee bere irin ajo igbagbo, sugbon iko-ara-eni-ni-ijanu ni yoo gbe e duro. Ki i se gbogbo igba ni o rorun lati gboran si Olorun tabi lati duro sibe ninu igbagbo, paapaa julo nigba ti o ba da wipe ipo wa ko yipada. Nigba yi ni iko-ara-eni-ni-ijanu yoo mu wa yàn lati duro le ileri Olorun bi ero ba ti le sa. Ki ileri kan to wá si imuse tan, awon igba idakeroro kan yoo wà lati dan ipamora wa wo. Opolopo ni yoo pa eyin da ni akoko iduro yi, sugbon awon ti o duro sinsin ni yoo jogun ileri na. Igbagbo ti o ni ipamora lagbara ju igbagbo ti o fe igbadun igbagbogbo. Je ki a ko irin re pelu Olorun sori ohun to ju erongba lasan lo. Je ki o gbinle ninu otito, igboran ati iko-ara-eni-ni-ijanu, ki o baa le duro titi de opin.
Asaro: Igbagbo ti o ni ipamora maa npe ju erongba lo.
BIBELI KIKA: Heberu 3:12-15
ADURA: Baba wa orun, fun mi ni agbara ati iko-ara-eni-ni-ijanu lati duro sinsin ninu igbagbo titi de opin. Amin.