FREE FROM COMPARISON

FREE FROM COMPARISON

THE SEED

“For we dare not class ourselves or compare ourselves with those who commend themselves. But they, measuring themselves by themselves, and comparing themselves among themselves, are not wise .” — 2 Corinthians 10:12

The world thrives on comparison, but God calls His children to a different path. Each person has a unique journey designed by God, and measuring your life by someone else’s path only breeds insecurity and discontentment. You can learn from others, admire their growth, and even emulate good virtues—but you cannot live their story. Likewise, no one can live yours. True wisdom is to focus on your God-given race with confidence and joy. Run your race without distraction. God’s timetable for your life is perfect and incomparable.

Reflection: God’s purpose for your life is unique—stay focused on your own race.

 

BIBLE READING: 2 Corinthians 10:12–18

PRAYER: Heavenly Father, help me to stop comparing myself with others and to run the race You set before me. Amen.

 

BO LOWO AFARAWE

IRUGBIN NAA:

“Nítorí pé àwa kò dáṣà láti ka ara wa mọ́, tàbí láti fi ara wa wé àwọn mìíràn nínú wọn tí ń yin ara wọn; ṣùgbọ́n àwọn fúnrawọn jẹ́ aláìlóye bí wọn ti ń fi ara wọn díwọ̀n ara wọ́n, tí wọ́n sì ń fi ara wọn wé ara wọn..sugbon awon tikarawon je alailoye nigbati won nfi ara won diwon ara won, ti won si nfi ara won we ara won.” –  II Korinti 10:12

Aye feran afarawe asan, sugbon Olorun pe awon omo Re si ipa ona miiran. Olukuluku eniyan lo ni irin ajo ti a ti ya soto, ti a ti seto lati owo Olorun – nitorina, fifi ara re diwon elomiran maa n fa ainiitelorun pelu ailoye. O le kọ́ ẹ̀kọ́ lati odo awon eniyan miiran, ki o se aferi igbega won, ati ki o se amulo iwa rere won, sugbon o ko le gbe igbe aye won. Bakanna, enikan ko le gbe tiwa. Ogbon otito ni lati fi oju si eré tire ti Olorun fun o pelu igboya ati ayo. Sá ere tire lai si ohun ikose. Eto Olorun fun aye re dara ko si ni afiwe.

Asaro: Ipinu Olorun fun aye re je eyi to yato, duro pelu afojusun ninu ere tire.

 

BIBLELI KIKA: II Korinti 10:12-18

ADURA: Baba wa orun, ran mi lowo lati si wo ninu fifi ara mi we pelu awon eniyan miiran ati lati sa ere ti o ti fi si iwaju mi. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *