GOD NEVER FAILS
THE SEED
“God is not a man, that he should lie; neither the son of man, that he should repent: hath he said, and shall he not do it? or hath he spoken, and shall he not make it good?” — Numbers 23:19 (KJV)
Throughout the ages, God has proven to be faithful to His Word. Unlike man, He does not change His mind or fail in His promises. Seasons may change, people may fail, but God remains steadfast. We can rest in the assurance that His promises are sure. Even when the timing seems long or the circumstances look impossible, God’s Word stands unshaken. He has the power and the will to fulfil everything He has spoken. Hold on to His promises with unwavering faith. He has never failed anyone who trusted Him, and He will not start with you.
Reflection: God’s promises never fail—they are sure and steadfast.
BIBLE READING: Numbers 23:19–20
PRAYER: Faithful Father, thank You because Your Word never fails. I rest in Your unfailing promises. Amen.
OLORUN KI I SE ASETI
IRUGBIN NAA:
“Ọlọrun ki iṣe enia ti yio fi ṣeké; bẹ̃ni ki iṣe ọmọ enia ti yio fi ronupiwada: a ma wi, ki o má si ṣe bi? tabi a ma sọ̀rọ ki o má mu u ṣẹ?” – Numeri 23:19
Lati igba atijo wa, Olorun ti fi han wipe O je olotito si oro Re. Ki i yi okan re pada tabi kuna ninu ileri Re gege bi eniyan ti nse. Akoko le yi pada, eniyan le kuna, sugbon Olorun wà sibe. Awa le sinmi ninu idaniloju wipe ileri Re daju. Nigba ti o ba tile da bi wipe ileri naa pe, tabi o ri bi wipe ko seese, oro Olorun duro lai yese. O ni agbara ati ife lati mu ohun gbogbo ti o ti so wa si imuse. Di ileri Re mu pelu igbagbo ti ki i yese. Ko ja enikeni ti o gbagbo ninu Re ku le ri, ko si ni bere pelu re.
Asaro: Ileri Olorun ki i ye, o daju, o si wa sibe.
BIBELI KIKA: Numeri 23:19-20
ADURA: Baba Olotito, O se nitori oro Re ki i ye. Mo sinmi ninu ileri Re ti ki yoo se alaiwa si imuse. Amin.