GOD’S MYSTERIOUS WAYS
THE SEED
“While Peter yet spake these words, the Holy Spirit fell on all them which heard the word.” — Acts 10:44
God does not always follow human expectations or patterns. The outpouring of the Spirit in Cornelius’ house happened suddenly, without the usual process. God bypassed protocols to show that His power is not limited by human systems.
This reminds us that God is sovereign. He works in unexpected ways to accomplish His purpose. No human structure or plan can stop what He has ordained. Trust His methods even when they surprise you. When God moves, He does so perfectly and at the right time.
Reflection: God is never limited by human methods or timelines.
BIBLE READING: Acts 10:23–48
PRAYER: Lord, let Your will and power prevail in my life beyond every human protocol. Amen.
ONA ARA OLORUN
IRUGBIN NAA:
“Bi Peteru si ti nsọ ọ̀rọ wọnyi li ẹnu, Ẹmí Mimọ́ bà le gbogbo awọn ti o gbọ́ ọ̀rọ na.” – Ise Awon Aposteli 10:44
Olorun ki i tẹ̀lé ero tabi ilana eniyan. Itujade Emi MImo ni ile Korneliu sele lojiji, lai tele ilana. Olorun fo gbogbo eto ti a la sile tele lati fihan wipe ilana eniyan ko di agbara Re lowo. Eyi nran wa leti wipe Olorun ni alagbara julo. O nrin ni ona ti a ko reti lati se asepe ise Re. Ilana tabi ète eniyan kankan ko le da ohun ti o ti yan lati se duro. Gbekele eto Re nigba ti o ba tile ya o lenu. Nigba ti Olorun ba gbe igbese, O maa nse ni asepe ati ni akoko ti o ye.
Asaro: Ilana ati akoko ti eniyan la sile ko le da Olorun duro.
BIBELI KIKA: Ise Awon Aposteli 10:23-48
ADURA: Oluwa, Je ki ase ati agbara Re bori gbogbo eto eniyan ninu aye mi. Amin.