ONLY THE PURE MAY ENTER

ONLY THE PURE MAY ENTER

THE SEED

“But there shall by no means enter it anything that defiles, or causes an abomination or a lie, but only those who are written in the Lamb’s Book of Life.” — Revelation 21:27 (NKJV)

Heaven is a holy city. Its gates are not merely architectural—they are moral. God’s dwelling is closed to whatever corrupts, deceives, or opposes His holiness. Entry is not negotiated by effort or pedigree, but granted by grace to those whose names are written in the Lamb’s Book of Life. Now is the time to be cleansed. Christ’s blood does not only forgive; it also purifies the heart and reshapes the life. Repentance is not a feeling—it is a turning: from defilement to devotion, from self-rule to the Spirit’s rule. Beloved, don’t postpone reconciliation. Tomorrow is not promised. Embrace righteousness today, and let the Holy Spirit keep your garments white.

Reflection: Purity is not optional where God dwells.

 

BIBLE READING: Revelation 21:22–27

PRAYER: Father, cleanse me by the blood of Jesus and keep me ready for Your holy city. Amen.

 

ÀWỌN ẸNI MÍMỌ́ NÌKAN NI Ó LÈ WỌLÉ

IRUGBIN NAA

“Ṣùgbọ́n kò sí ohunkóhun tí ó lè ba nǹkan jẹ́, tàbí tí ó lè fa ohun ìríra tàbí irọ́ tí yóò wọ inú rẹ̀ lọ́nàkọnà, bí kò ṣe àwọn tí a kọ sínú Ìwé Ìyè.” – Ìfihàn 21:27

Ọ̀run jẹ́ ìlú mímọ́. Àwọn ẹnu-ọ̀nà rẹ̀ kì í ṣe nipa amọ̀ bikose nipa ìwà.  wọ́n wà ní ìlú tí a ti sé ni mimo  Ibùgbé Ọlọ́run tì si awon onbàjẹ́, elẹ́tàn, àtí awon ti ó lòdì sí ìwà mímọ́ Rẹ̀. A kì í fi ojusajuū tàbí ipá ènìyàn wọlé, bikose nipa oore-ọ̀fẹ́ fún àwọn tí a kọ orúkọ wọn sínú Ìwé Ìyè Ọ̀dọ́-Àgùntàn. Àkókò nì yìí fun o láti wẹ ara re mọ́. Ẹ̀jẹ̀ Kristi kì í ṣe pé ó ń dáríjì nìkan; ó tún ń sọ ọkàn di mímọ́, ó sì ń tún ìgbésí ayée wa ṣe. Ìrònúpìwàdà kì í ṣe ìmọ̀lára lasn, ó jẹ́ ìyípadà: láti ìbàjẹ́ sí ìfọkànsìn, láti ìṣàkóso ara-ẹni sí ìṣàkóso Ẹ̀mí. Olùfẹ́ ọ̀wọ́n, ẹ má ṣe fi atunse dọ̀la. A kò ṣe ìlérí ọ̀la. Ẹ gba òdodo lónìí, kí ẹ sì jẹ́ kí Ẹ̀mí Mímọ́ pa aṣọ yín mọ́.

Asaro: Dandan ni Ìwà mímọ́ níbi tí Ọlọ́run ń gbé.

 

BIBELI KIKA: Ìfihàn 21:22-27

ADURA Baba, fi ẹ̀jẹ̀ Jésù wẹ mí mọ́ kí o sì mu mi wa imúra sílẹ̀ fún ilu Mimo re. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *