CITIZENS OF A HIGHER KINGDOM
THE SEED
“For our citizenship is in heaven, from which we also eagerly wait for the Savior, the Lord Jesus Christ.” — Philippians 3:20 (NKJV)
We may live in this world, but as believers, our true citizenship is in heaven. Our King is there, our names are registered there, and our inheritance awaits us there. This truth should shape how we live, speak, and make decisions daily. Heaven is not a distant hope for “someday” — it’s a present reality that governs the way we live on earth. Kingdom citizens live differently: they set their affection on things above and prioritize eternal values over temporary gains.
Beloved, one day your earthly journey will end, and the flight home will take place. Live ready. Live joyfully. Live purposefully — as one whose home is with the King of Glory.
Reflection: A heavenly citizen must live with eternity in view.
BIBLE READING: Philippians 3:17–21
PRAYER: Lord, help me to live as a faithful citizen of heaven, ready to return home at Your call. Amen.
ÀWỌN ỌMỌ-ÌBÍLẸ̀ ÌJỌBA GÍGA
IRUGBIN NAA
“Nitori ilu-ibilẹ wa mbẹ li ọrun: lati ibiti awa pẹlu gbé nfojusọna fun Olugbala, Jesu Kristi Oluwa:” – Fílípì 3:20 (NKJV).
A lè gbé ní ayé yìí, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí onígbàgbọ́, ìlú wa tòótọ́ wà ní ọ̀run. Ọba wa wà níbẹ̀, orúkọ wa wà níbẹ̀, ogún wa sì ń dúró dè wá níbẹ̀. Òtítọ́ yìí yẹ kí ó ṣe àtúnṣe bí a ṣe ń gbé ìgbésí ayé, ọ̀rọ̀, àti ìpinnu wa lójoojúmọ́. Ọ̀run kì í ṣe ìrètí jíjìnnà fún wa, nibayi , ó jẹ́ òtítọ́ ìsinsìnyí tí ó ń ṣàkóso bí a ṣe ń gbé ayé wa. Àwọn ọmọ-ìbílẹ̀ Ìjọba orun ń gbé ní ọ̀nà ti o yàtọ̀ si aye: wọ́n gbé ìfẹ́ wọn ka àwọn nǹkan tí ó wà lókè wọ́n sì ń fi àwọn ìníyelórí ayérayé sí ipò àkọ́kọ́ ju àwọn èrè ìgbà díẹ̀ lọ. Olùfẹ́, ní ọjọ́ kan ìrìn àjò ayé rẹ yóò parí, ti a o si mu o rele. Gbé ní ìmúrasílẹ̀. Gbé ní ayọ̀. Gbé pelu ipinnu gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ilé rẹ̀ wà pẹ̀lú Ọba Ògo.
Asaro: Ọmọ-ìbílẹ̀ ọ̀run gbọ́dọ̀ gbé pẹ̀lú ìyè àìnípẹ̀kun ní ojú ìwòye.
BIBELI KIKA: Fílípì 3:17-21
ADURA: Olúwa, ràn mí lọ́wọ́ láti gbé gẹ́gẹ́ bí ọmọ orílẹ̀-èdè ọ̀run olóòótọ́, tí o múra tán láti padà sílé nígbà tí o bá pè mí. Àmín.