CONTENTMENT: GOD’S QUIET GIFT

CONTENTMENT: GOD’S QUIET GIFT

THE SEED

“That each of them may eat and drink, and find satisfaction in all their toil—this is the gift of God.” — Ecclesiastes 3:13 (NIV)

Contentment is not passivity; it is worship. It frees us from chasing every new desire and helps us enjoy what God has already provided. Without it, we confuse wants with needs and live exhausted by endless comparison. Godly satisfaction teaches us to receive our portion with gratitude, to steward well without grasping, and to love who God made us to be. It quiets envy and curbs vanity, allowing joy to grow in ordinary days. Ask God for this gift. In contentment, you’ll find freedom to pursue purpose without being mastered by possessions.

Reflection: Contentment turns provision into praise.

 

BIBLE READING: Ecclesiastes 5:18–20

PRAYER: Father, fill my heart with divine satisfaction so I can enjoy and steward Your gifts well. Amen.

 

ÌTẸ́LỌ́RÙN: Ẹ̀BÙN ỌLỌ́RUN NI

IRUGBIN NAA

“Ati pẹlu ki olukulùku enia ki o ma jẹ ki o si ma mu, ki o si ma jadùn gbogbo lãla rẹ̀, ẹ̀bun Ọlọrun ni.” – Oníwàásù 3:13

Ìtẹ́lọ́rùn kì í ṣe oro lasan; ó jẹ́ ìsìn si Olorun. Ó ń tú wa sílẹ̀ kúrò nínú lílépa gbogbo ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́, ó sì ń ràn wá lọ́wọ́ láti gbádùn ohun tí Ọlọ́run ti pèsè tẹ́lẹ̀. Láìsí itelorun, a máa da ohun ti a fẹ́ pọ̀ mọ́ ohun ti a nílò , a sì máa ń gbé ìgbésí ayé ti n se àfarawé asán. Ìtẹ́lọ́rùn Ọlọ́run ń kọ́ wa láti gba ìpín wa pẹ̀lú ọpẹ́, láti je ojise ti ko se ojukokoro, àti láti fẹ́ ẹni tí Ọlọ́run dá wa láti jẹ́. Ó ń pa owú lenu mọ́, ó sì ń dín asán kù, ó ń jẹ́ kí ayọ̀ dàgbà ní àwọn ọjọ́. Béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ẹ̀bùn yìí. Nínú ìtẹ́lọ́rùn, ìwọ yóò rí òmìnira láti lépa ipinnu Olorun fun ọ láìsí pé àwọn ohun ìní ni ó ń darí rẹ.

Asaro: Ìtẹ́lọ́rùn ń yí ìpèsè padà sí ìyìn.

 

BIBELI KIKA: Oníwàásù 5:18-20

ADURA: Bàbá, fi ìtẹ́lọ́rùn àtọ̀runwá kún ọkàn mi kí n lè gbádùn àti láti ṣàkóso àwọn ẹ̀bùn Rẹ dáadáa.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *