BEYOND THE MASK

BEYOND THE MASK

THE SEED

“Woe unto you… for ye are like unto whited sepulchres, which indeed appear beautiful outward, but are within full of dead men’s bones…” — Matthew 23:27 (KJV)

Hypocrisy polishes the exterior while neglecting the interior. It sings loud, serves often, and judges quickly—yet guards secret sin. Jesus’ strongest words were reserved for religious pretense because it deceives others and deadens the soul.

The house of God is meant to be a place of truth, repentance, and transformation. Public devotion without private surrender is brittle; it cracks under pressure. The cure is not performance, but honesty before God and obedience to His Word. Invite the Spirit’s light into your motives. Seek accountability. Let your private life fuel your public worship. God desires truth in the inward parts.

Reflection: God is not impressed by masks; He heals the sincere.

 

BIBLE READING: Matthew 23:25–28

PRAYER: Lord, purge pretense from my heart. Make my inner life true and pleasing to You. Amen.

 

LEHIN IBOJU

IRUGBIN NAA

“Egbé ni fun nyin, ẹnyin akọwe ati Farisi, agabagebe; nitoriti ẹnyin dabi ibojì funfun, ti o dara li ode, ṣugbọn ninu nwọn kún fun egungun okú, ati fun ẹgbin gbogbo.” – Mátíù 23:27

Àgàbàgebè máa ń setoju òde nígbà tí ó si fojú fo inú. Ó ń kọrin sókè, ó ń ṣe ìránṣẹ́ nígbà gbogbo, ó sì ń ṣe ìdájọ́ kíákíá  síbẹ̀ ó ń dáàbò bo ẹ̀ṣẹ̀ ìkọ̀kọ̀. Jésù ba ìsìn etan wí kíkankíkan nítorí pé ó ń tan àwọn ẹlòmíràn jẹ, ó sì ń sọ ọkàn di òkú. Ilé Ọlọ́run ni a ṣe láti jẹ́ ibi òtítọ́, ìrònúpìwàdà, àti ìyípadà. Ìfọkànsìn afojuri láìsí ìfarajì ara ẹni jẹ́ aláìlágbára; ó ń subu lábẹ́ idanwo. Aṣehan ko le wò ó sàn, bí kò ṣe nipa  òtítọ́ níwájú Ọlọ́run àti ìgbọràn sí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀. Pe ìmọ́lẹ̀ Ẹ̀mí wá sínú èrò rẹ. Wá ìjíhìn. Jẹ́ kí ìgbésí ayé ìkọ̀kọ̀ rẹ máa fún ìjọsìn rẹ ní gbangba lágbára. Ọlọ́run fẹ́ òtítọ́ inú.

Asaro: Olorun kò fẹ́ ìbòjú ẹ́tàn; Ó ń wo àwọn olóòótọ́ sàn.

 

BIBELI KIKA: Mátíù 23:25-28

ADURA: Olúwa, mú àṣehàn kúrò nínú ọkàn mi. Jẹ́ kí ìgbésí ayé inú mi jẹ́ òótọ́ kí ó sì dùn mọ́ ọ. Àmín.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *