GIVE GOD HIS GLORY

GIVE GOD HIS GLORY

THE SEED

“I am the LORD; that is my name; my glory I give to no other.” — Isaiah 42:8 (ESV)

Taking credit for what God has done is more than bad manners—it’s robbery. Nebuchadnezzar learned this painfully when pride seized his tongue and sovereignty left his throne. Every strength, insight, connection, and breath is a trust from God. Spiritual “plagiarism” happens whenever we showcase outcomes but silence the true Source. Gratitude rights the heart. Testimony redirects applause. Humility keeps the channel open. Choose attribution over ambition. Acknowledge God in your success, and He will keep enlarging your stewardship without endangering your soul.

Reflection: Glory belongs to God; gratitude belongs to us.

 

BIBLE READING: Daniel 4:28–37

PRAYER: Lord, deliver me from pride. Teach me to honor You as the Source of every good thing. Amen.

 

FI ÒGO FÚN ỌLỌ́RUN

IRUGBIN NAA

“Emi li Oluwa: eyi ni orukọ mi: ogo mi li emi kì yio fi fun ẹlòmiran, bẹ̃ni emi kì yio fi iyìn mi fun ere gbigbẹ́.” – Isaiah 42:8 (ESV)

Gbígba ògo tí o ye fún Ọlọ́run koja ìwà búburú lọ – olè jíjà ni. Nebukadnessari kọ́ èyí pẹ̀lú ìrora nígbà tí ìgbéraga gba ahọ́n rẹ̀ ti agbara si fi ìtẹ́ rẹ̀ sílẹ̀. Gbogbo agbára, òye, ìsopọ̀, àti èémí jẹ́ ìgbẹ́kẹ̀lé láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run. Ìwà ole ni nígbàkúgbà tí a bá fi owo rọ́ Orisun ibukun sehin ti a si fi àbájáde nikan hàn. Ìdúpẹ́ ń tọ́ ọkàn sọ́nà. Ẹ̀rí ń darí ìyìn si odo Olorun. Ìrẹ̀lẹ̀ ń jẹ́ kí ọ̀nà ṣí sílẹ̀. Yan ìfàmọ́ra ju ìfẹ́ ọkàn lọ. Mọ Ọlọ́run nínú àṣeyọrí rẹ, yóò sì máa mú ọ gbòòrò sí i láìfi ẹ̀mí rẹ wewu.

Asaro: Ògo jẹ́ ti Ọlọ́run; ọpẹ́ jẹ́ tiwa.

 

BIBELI KIKA:  Dáníẹ́lì 4:28-37

ADURA: Olúwa, gbà mí lọ́wọ́ ìgbéraga. Kọ́ mi láti bu ọlá fún ọ gẹ́gẹ́ bí Orísun ohun rere gbogbo.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *