KEEP THE FIRE BURNING
THE SEED
“The fire shall ever be burning upon the altar; it shall never go out.” — Leviticus 6:13 (KJV)
In the Old Testament, priests kept the fire burning continually to ensure that sacrifices were always acceptable before God. In Christ, we no longer bring animal offerings, but we ourselves are the living altar of God. The fire now represents the Holy Spirit in us. A burning altar reflects a vibrant, unbroken relationship with God. Prayer, worship, and the Word keep this fire alive. If the fire dims, spiritual coldness sets in, making the heart vulnerable to distraction. Beloved, don’t let the flame go out. Keep the fire burning daily through communion with the Holy Spirit.
Reflection: A burning altar is proof of a living relationship with God.
BIBLE READING: Leviticus 6:8–13
PRAYER: Lord, set my heart on fire for You. Help me keep the flame of Your Spirit alive always. Amen.
JẸ́ KÍ INÁ MÁA JÍJÓ
IRUGBIN NAA
“Ki iná ki o ma jó titi lori pẹpẹ na; kò gbọdọ kú lai.” – Léfítíkù 6:13
Nínú Májẹ̀mú Láéláé, àwọn àlùfáà máa mú iná ori pẹpẹ jó nígbà gbogbo láti rí i dájú pé ẹbọ jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà níwájú Ọlọ́run. Nínú Kristi, a kò mú ẹbọ ẹranko wá mọ́, ṣùgbọ́n àwa fúnra wa ni pẹpẹ alààyè ti Ọlọ́run. Iná náà tọ́ka sí Ẹ̀mí Mímọ́ nínú wa nísinsìnyí. Pẹpẹ tí ń jó ń se afihàn ajosepo to dánmọ́rán pẹ̀lú Ọlọ́run. Àdúrà, ìsìn, àti Ọ̀rọ̀ ń mú kí iná yìí wà jó. Tí iná yii bá rẹ̀, òtútù ẹ̀mí a bẹ̀rẹ̀, yó si mu ki okan wa ni ewu ìfàsẹ́hìn. Olùfẹ́ ọ̀wọ́n, má ṣe jẹ́ kí iná náà kú. Jẹ́ kí iná náà máa jó lójoojúmọ́ nípasẹ̀ ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Ẹ̀mí Mímọ́.
Asaro: Pẹpẹ tí ń jó jẹ́ ẹ̀rí ìbáṣepọ̀ alààyè pẹ̀lú Ọlọ́run.
BIBELI KIKA: Léfítíkù 6:8-13
ADURA: Olúwa, mú kí ọkàn mi máa jó fún ọ. Ràn mí lọ́wọ́ láti pa iná Ẹ̀mí Rẹ mọ́ nígbà gbogbo.